FUN mi n’ iwa pele
FUN mi n’ iwa pele, Okan tutu; Ifarabale bi T’ Oluwa mi;
Read hymn : FUN mi n’ iwa pele643 hymns
FUN mi n’ iwa pele, Okan tutu; Ifarabale bi T’ Oluwa mi;
Read hymn : FUN mi n’ iwa peleFUN ‘rugbin l’ owuro, irugbin inu ‘re Funrugbin l’ osan gan, ati ni ale Duro de ikore ati ‘gba ikojo A o f’ ayo pada, ru iti wole.
Read hymn : FUN ‘rugbin l’ owuro, irugbin inu ‘reFUNRUGBIN l’ owuro, Ma simi tit’ ale; F’ eru on ‘yemeji sile Ma fon s’ ibi gbogbo.
Read hymn : FUNRUGBIN l’ owuroF’ AWON enia Re t’ o lo ‘smi Awon ti o f’ igbagbo jewo Re, Ki yin oruko Re, Olugbala, Alleluya!
Read hymn : F’ AWON enia Re t’ o lo ‘smiF’ ERU re f’ afefe, N’ ireti, ma foya, Olorun gbo ‘mikanle re, Yiop gb’ ori re ga.
Read hymn : F’ ERU re f’ afefeF’ ORUK’ Olorun loke, T’ O l’ agbara at’ ola, Olorun ibi gbogbo, N’ iyin ati ogo wa.
Read hymn : F’ ORUK’ Olorun lokeF’ORUKO Jesu s’ okan re Om’ egbe on ‘banuje; Yio fun o l’ayo oun ‘tunu Gbee wo lo s’ibi gbogbo
Read hymn : F’ORUKO Jesu s’ okan reGBA aiye mi, Oluwa, Mo ya si mimo fun O; Gba gbogbo akoko mi, Ki nwon kun fun iyin Re.
Read hymn : GBA aiye mi, OluwaGBA alare nwa sinmi, Ti nwon w’odo Re; Gba nwon ko ‘banuje won Wa si ‘waju Re;
Read hymn : GBA alare nwa sinmiGBA Jesu ba de lati pin ere, B’ o j’ osan tabi l’ oru, Y’o ha ri wa nibit’ a gbe ns’ ona, Pel’ atupa wa tin tan?
Read hymn : GBA Jesu ba de lati pin ereGBA mo le ka oye mi re, Ni ibugbe l’oke; Mo dagbere f’eru gbogbo, Mo n’omije mi nu.
Read hymn : GBA mo le ka oye mi reGBA t’ Olugbala w’ aiye, Anu j’ oba l’ okan Re, O nfi ibakedun han K’ O si gan enikeni.
Read hymn : GBA t’ Olugbala w’ aiye