GBAT’ okan are fe ‘simi
GBAT’ okan are fe ‘simi, T’ o nwa Olorun re, B’ o ti dun to lati r’ ale T’ o pin ose lala.
Read hymn : GBAT’ okan are fe ‘simi643 hymns
GBAT’ okan are fe ‘simi, T’ o nwa Olorun re, B’ o ti dun to lati r’ ale T’ o pin ose lala.
Read hymn : GBAT’ okan are fe ‘simiGBEKE re le Oluwa, F’ oro Re s’ agbara re; Y’o duro ti o lailai, B’ orun tile koja lo.
Read hymn : GBEKE re le OluwaGBEKELE ojojumo, ‘Gbekele ninu iji, B’ igbgbo tile kere, Ki nsa gbekele Jesu.
Read hymn : GBEKELE ojojumoGBEKELE onigbagbo, B’ ija na tile pe, Sibe iwo yio segun, Olorun ja fun o.
Read hymn : GBEKELE onigbagboGBO ase ti Jesu pa, “Lo wasu ‘hinrere Mi, Enikeni t’ o gbagbo, T’ a si tebomi, yio la.”
Read hymn : GBO ase ti Jesu paGBO eda orun nkorin, “Ogo fun Oba t’ a bi.” “Alafia l’ aiye yi,” Olorun ba wa laja,
Read hymn : GBO eda orun nkorinGBO elese, Anu npe o, Ohun didun l’Ofi npe O nke yara w’Olugbala, K’owo are to subu;
Read hymn : GBO elese, Anu npe oGBO l’ or’ ite Re, Alade, F’ oniruru ‘bukun ranse, B’ awon omo Re ti nwa O, Gb’ adura t’ oro Re ko ni.
Read hymn : GBO l’ or’ ite Re, AladeGBO ohun alore, Ji, ara, ji: Jesu ma fere, de, Ji, ara, ji
Read hymn : GBO ohun aloreGBO ohun Jesu ti nke pe, Tani yio sise loni? Oko pon pupo sise loni? Tani yio lo ka a?
Read hymn : GBO ohun Jesu ti nke peGBO ohun t’ o dun lat’ oke Si Jesu l’ odo Jordani, Eri fun gbogbo araiye, “Eyi l’ ayanfe Omo Mi.”
Read hymn : GBO ohun t’ o dun lat’ okeGBO okan mi, bi Angeli ti nkorin, Yika orun ati yika aiye; E gbo bi oro orin won ti dun to! Ti nso ‘gbati ese ki y’o si mo:
Read hymn : GBO okan mi, bi Angeli ti nkorin