GB’ opo duru pelu ohun
GB’ opo duru pelu ohun Nwon nkorin iyin loke; Jesu joba, orun si yo; Olorun ife joba;
Read hymn : GB’ opo duru pelu ohun643 hymns
GB’ opo duru pelu ohun Nwon nkorin iyin loke; Jesu joba, orun si yo; Olorun ife joba;
Read hymn : GB’ opo duru pelu ohunGB’ ori soke alare, Tori ayo nbo l’ owuro, Olorun so n’nu oro Re Pe ayo ma nbo l’ owuro,
Read hymn : GB’ ori soke alareHA! egbe mi, e w’ asia Bi ti nfe lele Ogun Jesu fee de na, A fere segun!
Read hymn : HA! egbe mi, e w’ asiaHALLELUYAH, Halleluyah, E gbe ohun ayo ga, E korin inudidun, K’ e si yin olorun wa,
Read hymn : HALLELUYAH, HalleluyahIBU ife! O le je Pe a p’anu mo fun mi; Olorun mi ha le da ‘Binu ro fun elese?
Read hymn : IBU ife! O le jeIBUKUN ni f’ oku, T’ o simi le Jesu; Awon t’ o gb’ ori won Le okan aiya Re.
Read hymn : IBUKUN ni f’ okuIFE lo to bayi? Ohun gbogbo pari, O ti pari gbogbo ise T’ O tori re w’ aiye.
Read hymn : IFE lo to bayiIFE l’ Olorun: anu Re Mole s’ ona wa gbogbo; O ns’ ayo ji, O ndin ‘se ku: Ogbon nla ni olorun.
Read hymn : IFE l’ Olorun: anu ReIFE mi s’ ibi ti wa pe, Lai beru itiju, Titi mo fi r’ ohun titun, Ti o da mi duro.
Read hymn : IFE mi s’ ibi ti wa peIFE orun alailegbe, Ayo orun sokale: Fi okan wa se ‘bugbe Re, Se asetan anu Re;
Read hymn : IFE orun alailegbeIFE orun t’ o teriba Lati pin ninu ekun wa: Iwo l’ a k’ aniyan wa le, Ko si nkan gbat’ O sunmo wa.
Read hymn : IFE orun t’ o teribaIFE orun! alailegbe! N’nu ase mimo yi, Ogo re kun, ‘mole re po, Ti ntan iye jade.
Read hymn : IFE orun! alailegbe