A YIN O ‘lorun, nitor’ Omo ‘fe Re
A YIN O ‘lorun, nitor’ Omo ‘fe Re, Fun Jesu ti o ku to si lo soke
Read hymn : A YIN O ‘lorun, nitor’ Omo ‘fe Re643 hymns
A YIN O ‘lorun, nitor’ Omo ‘fe Re, Fun Jesu ti o ku to si lo soke
Read hymn : A YIN O ‘lorun, nitor’ Omo ‘fe ReA! mba le l’ egberun ahon. Fun ‘yin Olugbala, Ogo Olorun Oba mi, Isegun ore Re.
Read hymn : A! mba le l’ egberun ahonA! RO ti ibugbe orun, Li eba odo imole, Nibit’ awon mimo wa l’ aiku, T’ a wo won li aso funfun.
Read hymn : A! RO ti ibugbe orunA, JEKI oro mimo Re Fi agbara si okan mi, F’ imole at’ ife orun Wi f’ okan mi pe, “Wo t’ emi.”
Read hymn : A, JEKI oro mimo ReA, JESU Alabukun, A m’ orin ayo wa, Ohun at’ okan ‘pe wa L’ ayo l’ a gbe si O;
Read hymn : A, JESU AlabukunABA le n’ igbagbo aye, B’ o ti wu k’ ota po; Igbagbo ti ko je mira Fun aini at’ os
Read hymn : ABA le n’ igbagbo aye“ABBA, Baba,” a sunmo O L’ oruko Jesu owon; Aw’ omo Re t’ o pe nihin, Nfe ‘bukun t’ O se ‘leri;
Read hymn : ABBA, Baba,” a sunmo OABE, a fe ri o, Ojo ‘simi rere, Gbogbo ose a ma wipe, Iwo o ti pe to?
Read hymn : ABE, a fe ri oADUA didun adua didun, T’o gbe mi lo kuro l’aiye, Lo ‘waju ite Baba mi, Ki nso gbogbo edun mi fun;
Read hymn : ADUA didun adua didunAFRIK’ ‘le wara at’ oyin, Ni orile aiye now si, T’ Olorun fun ania dudu, Fun ini re titi lailai.
Read hymn : AFRIK’ ‘le wara at’ oyinAFUN iho ayo mimu S’ Olorun Oba nla! K’ile gbogbo lo ahon won K’o si korin ‘segun.
Read hymn : AFUN iho ayo mimuAGBELEBU ni ere mi, Nibe ni a rubo fun mi; Nibe l’ a kan Oluwa mo Nibe l’ Olugbala mi ku.
Read hymn : AGBELEBU ni ere mi