IWO low’ Enit’ ire nsan
IWO low’ Enit’ ire nsan, Mo gb’ okan mi si O; N’ ibanuje at’ ise mi, Oluwa ranti mi.
Read hymn : IWO low’ Enit’ ire nsan643 hymns
IWO low’ Enit’ ire nsan, Mo gb’ okan mi si O; N’ ibanuje at’ ise mi, Oluwa ranti mi.
Read hymn : IWO low’ Enit’ ire nsanIWO Oro Olorun, Ogbon at’ oke wa, Oto ti ki ‘yipada, Imole aiye wa;
Read hymn : IWO Oro OlorunIWO oro t’o tobi, Ninu eyit ‘a ri, Ileri ati sise Awamaridi ni:
Read hymn : IWO oro t’o tobiIWO ti gbogbo eda nsin L’ ara erupe yi, Bi O tit obi to l’aiye! B’ ogo Re ti po to!
Read hymn : IWO ti gbogbo eda nsinIWO ti okunkun Gb’ oro agbara Re, T’ o si fo lo; Gbo ti wa, a mbe O,
Read hymn : IWO ti okunkunIYE wa ni wiwo, Enit a kan mo ‘gi Iye wa nisisiyi fun o; Nje wo O elese k’ o le ri igbala, Wo Enit’ a kan mo ‘gi fun o.
Read hymn : IYE wa ni wiwo, Enit a kan mo ‘giJE ni imole ojo Para kuro loju mi, Lala mi rekoja lo, Ngo ba Oluwa soro.
Read hymn : JE ni imole ojoJE ran orun kekere nibiti o nlo, Se ranlowo lati le okunkun l’ aiye, ‘Wo o ri b’ okunkun yio ti lo kuro, B’ iwo ba je ‘mole njojumo.
Read hymn : JE ran orun kekere nibiti o nloJE, Oluwa, sin wa jeje, L’ aiye omije yi ja, Si fun wa l’ ore-ofe Re Ninu eru wa gbogbo:
Read hymn : JE, Oluwa, sin wa jejeJEJE, lai si ariwo, Jeje li orun nran, Gbat’ o bay o n’ ila re, Eda le w’ oju re;
Read hymn : JEJE, lai si ariwoJEKI m’ n’ ipo mi lodo Re, Jesu, Iwo isimi mi; ‘Gbana l’ okan mi y’o simi Y’o si ri ekun ‘bukun gba.
Read hymn : JEKI m’ n’ ipo mi lodo ReJEK’ alore Sion dide Gba ipe fun ‘ra won; Jeki nwon gba ase wuwo Lat’ enu Oluwa.
Read hymn : JEK’ alore Sion dide