JESU l’ Olusagutan mi
JESU l’ Olusagutan mi, Ore Eniti ki ye! Ko s’ ewu bi mo je Tire, T’ On sije t’ emi titi.
Read hymn : JESU l’ Olusagutan mi643 hymns
JESU l’ Olusagutan mi, Ore Eniti ki ye! Ko s’ ewu bi mo je Tire, T’ On sije t’ emi titi.
Read hymn : JESU l’ Olusagutan miJESU ma to wa Tit’ ao fi simi; Bi ona wa ko tile dan, A o tele O l’ aifoya;
Read hymn : JESU ma to waJESU mo bg’ agbelebu mi, Ki nle ma to O lehin; Otosi at’ eni egan, ‘Wo l’ ohun gbogbo fun mi;
Read hymn : JESU mo bg’ agbelebu miJESU nfe gba elese,, Kede re fun gbogb’ eda; T’o yapa ona ‘run ‘le, At’ awon ti njafara.
Read hymn : JESU nfe gba eleseJESU nfe k’ a f’ imole ti o pe tan, Bi fitila kekere ninu oru; L’ aiye okunkun yi, ka si tan, N’ ipo t’ iwo wa, at’ emi pelu.
Read hymn : JESU nfe k’ a f’ imole ti o pe tanJESU nf’ ohun jeje pe o wa ‘le O npe loni, o npe loni! Ese t’ o fi ko ife Re sile, T’ o sako jinna rere?
Read hymn : JESU nf’ ohun jeje pe o wa ‘leJESU ni gbogb’ aiye fun mi, Iye at’ ayo mi, Agbara mi lojojumo, L’ aisi Re mo subu;
Read hymn : JESU ni gbogb’ aiye fun miJESU ni, “Gb’ agbelebu re Ki o si ma tele Mi,” Oro yi ha le mu wag bon? A o ha sa fun eru na?
Read hymn : JESU ni, “Gb’ agbelebu reJESU nigba ‘danwo, Gbadua fun mi; K’ emi ma ba se O, Ki nsi sako lo:
Read hymn : JESU nigba ‘danwoJESU npe wa l’ osan, l’ oru Larin irumi aiye; Lojojumo l’ a ngb’ ohun Re Wipe, “Kristian, tele Mi.”
Read hymn : JESU npe wa l’ osan, l’ oruJESU np’ enia Re S’ ori tabili Re, Nibi l’ awon t’ a dariji Nb’ Oluwa won dapo.
Read hymn : JESU np’ enia ReJESU o ye ki nl’ ayo, Ti mba le gbekele O, Pe ogbon Re to to mi, Pe ore Re to pese,
Read hymn : JESU o ye ki nl’ ayo