JESU ye; titi aiye
JESU ye; titi aiye Eru iku ko ba ni mo; Jesu ye; nitorina Isa oku ko n ‘ipa mo. – Alleluya!
Read hymn : JESU ye; titi aiye643 hymns
JESU ye; titi aiye Eru iku ko ba ni mo; Jesu ye; nitorina Isa oku ko n ‘ipa mo. – Alleluya!
Read hymn : JESU ye; titi aiyeJESU y’o joba ni gbogbo Ibit’ a ba le ri orun; ‘Joba Re y’o tan kakiri, ‘Joba Re ki o n’ ipekun.
Read hymn : JESU y’o joba ni gbogboJESU ‘ wo Onisegun nla, T’ olokunrun nf’ ailera mo, Nigba aisan at’ irora, O se dida ara fun won.
Read hymn : JESU ‘ wo Onisegun nlaJESU, a fe pade, L’ ojo Re mimo yi; A si y’ ite Re ka, L’ ojo Re mimo yi;
Read hymn : JESU, a fe padeJESU, agbara mi, Iwo l’ aniyan mi, Emi fi igbagbo w’ oke, Iwo l’ O ngb’adua.
Read hymn : JESU, agbara miJESU, aso ododo Re L’ ewa at’ ewu ogo mi, L’ aiye etan bi mba gbe wo, L’ ayo ni ngo gb’ ori s’ oke.
Read hymn : JESU, aso ododo ReJESU, bukun wa k’ a to lo: Gbin oro Re si aiya wa: K’ o si mu k’ ife gbigbona Kun okan ilowo wa:
Read hymn : JESU, bukun wa k’ a to loJESU, ise Re l’o Fi ayo s’okan mi, Nwon ni, o ti pari, Ki eru mi ko tan:
Read hymn : JESU, ise Re l’oJESU, Iwo li a nwo, K’ a repo l’ oruko Re; Alade alafia, Mu k’ ija tan larin wa.
Read hymn : JESU, Iwo li a nwoJESU, nib’ eni Re pade, Nibe nwon r’ ite anu Re; Nibe nwon wa O, nwon ri O, Ibikibi n’ ile owo.
Read hymn : JESU, nib’ eni Re padeJESU, O ha re ‘ra Re le Gbat’ O gb’ ara wa wo? Lati se awotan aisan, Lati l’ arun jade?
Read hymn : JESU, O ha re ‘ra Re leJESU, Oba nla ni Sion, ‘Wo ni yio j’ amona wa; Ase Re li a gbekele, Iwo nikan l’ ao tele.
Read hymn : JESU, Oba nla ni Sion