KABO ojo rere, ” l’ ao ma wi titi
KABO ojo rere, ” l’ ao ma wi titi; A sete ‘ku loni, orun di tiwa. ‘Wo oku d’ alaye, oba tit’ aiye, Gbogb’ eda Re, Jesu, ni nwon njuba Re.
Read hymn : KABO ojo rere, ” l’ ao ma wi titi643 hymns
KABO ojo rere, ” l’ ao ma wi titi; A sete ‘ku loni, orun di tiwa. ‘Wo oku d’ alaye, oba tit’ aiye, Gbogb’ eda Re, Jesu, ni nwon njuba Re.
Read hymn : KABO ojo rere, ” l’ ao ma wi titiKABO ojo ‘simi T’ o r’ ajinde Jesu; Ma bowa s’ okan ti nsoji, At’ oju ti nyo yi!
Read hymn : KABO ojo ‘simiKEFERI nsegbe lojojo, Egbegberun l’ o nkoja lo; Mura Kristian s’igbala won, Wasu fun won ki nwon to ku.
Read hymn : KEFERI nsegbe lojojoKI a to d’ awon oke nla, Tabi ki aiye to duro, Ki a to da awon igba, ‘Wo l’ Olorun lat’ ibere.
Read hymn : KI a to d’ awon oke nlaKI nko ohun gbogbo sile Fun O, Oluwa mi O to be, niwon b’ O ti se Rekoja ‘yi fun mi.
Read hymn : KI nko ohun gbogbo sileKI sepe mo ko yan O, Oluwa, ko ri be, Okan mi iba ko O, Sugbon ‘Wo l’ o yan mi.
Read hymn : KI sepe mo ko yan OKIKU n’nu Jesu, iku re T’ a ki ji sinu re sokun, Isimi t’ o ni itura, Ti iku ko le yo lenu.
Read hymn : KIKU n’nu Jesu, iku reKIL’ o le w’ ese mi nu? Ko si, lehin eje Jesu; Kil’ o tun le wo mi san? Ko si, lehin eje Jesu.
Read hymn : KIL’ o le w’ ese mi nuKINI gbogbo lala Re L’ ori mi fun, Jesu, At’ anfani t’ O fun mi Ju awon miran lo?
Read hymn : KINI gbogbo lala ReKO mi ni iwon ojo mi, Iwo Eleda mi; Mo fe w’ ona toro aiye, Ki nmo ailera mi.
Read hymn : KO mi ni iwon ojo miKO mi, Oluwa mi, Ki nr’ owo Re yika, Ki nsi ma se ohun gbogbo, Bi enipe fun O.
Read hymn : KO mi, Oluwa miKO si ewa nibikan ti Mo le fi we ti Krist’: Ohun t’ oku, Oluwa, ni K’ a je ‘kan pelu Re.
Read hymn : KO si ewa nibikan ti