KO s’ aye ‘jafara nihin
KO s’ aye ‘jafara nihin Fun ‘reti at’ eru aiye; B’ emi ki ba pe bo, B’ o ba je pe b’ Onidajo
Read hymn : KO s’ aye ‘jafara nihin643 hymns
KO s’ aye ‘jafara nihin Fun ‘reti at’ eru aiye; B’ emi ki ba pe bo, B’ o ba je pe b’ Onidajo
Read hymn : KO s’ aye ‘jafara nihinKO s’ ohun t’ o ku kin se, B’ o ti wu k’ o kere; Jesu ku, O san gbogbo Igbese ti mo je.
Read hymn : KO s’ ohun t’ o ku kin seKo s’ ona si ayo orun, S’ ayo at’ alafia toto, Lehin Jesu, Ona; Jek’ a rin l’ ona mimo na,
Read hymn : Ko s’ ona si ayo orunKO s’ ore bi Jesu onirele, Ko s’ okan! Ko s’ okan! Ko s’ elomi t’ o le w’ okan wa san, Ko s’ okan! Ko s’ okan!
Read hymn : KO s’ ore bi Jesu onireleKO to k’ awon mimo beru, Ki nwon so ‘reti nu; ‘Gba nwon ko reti ‘ranwo Re, Olugbala yio de.
Read hymn : KO to k’ awon mimo beruKRIST, ologo, olola, Iwo Imole aiye, Orun ododo, dide, K’ O si bori okunkun;
Read hymn : KRIST, ologo, ololaKRISTI fun gbogb’ aiye Ise nla naa bere Egbegberun ni gbogb’ aiye, Nfe gb’ oro ‘mo ‘Lorun
Read hymn : KRISTI fun gbogb’ aiyeKRISTI n’ ipile wa, Lori Re lao kole; Awon mimo nikan, L’ o ngb’ agbala orun.
Read hymn : KRISTI n’ ipile waKRISTIAN ma ti wa ‘simi, Beli angeli re nwi, Ni arin ota l’ owa, Ma sora.
Read hymn : KRISTIAN ma ti wa ‘simi,KRIST’ ki ‘joba Re de, Ki ase Re bere; F’ opa-rin Re fo Gbogbo ipa ese.
Read hymn : KRIST’ ki ‘joba Re deKRIST’ Oluwa ji loni, – Halleluyah, Eda at’ Angeli nwi – Hal. Gb’ ayo at’ isegun ga – Hal. K’ orun at’ aiye gberin! – Hal.
Read hymn : KRIST’ Oluwa ji loni, – HalleluyahKRIST’, nin’ ogba Eden, L’ a gbe ti ri r’ ase yi, Ase Tire, P’ o ye f’ eni meji
Read hymn : KRIST’, nin’ ogba Eden