MASE huwa ese
MASE huwa ese, Ma soro ese; Omo Jesu l’ e se, Omo Oluwa.
Read hymn : MASE huwa ese643 hymns
MASE huwa ese, Ma soro ese; Omo Jesu l’ e se, Omo Oluwa.
Read hymn : MASE huwa eseMIMO, mimo, mimo! Olodumare! Ni kutukutu n’Iwo o gbo orin wa; Mimo, mimo, mimo! Oniyonu julo! Ologo meta lai, Olubukun!
Read hymn : MIMO, mimo, mimo! Olodumare!mJE k’ agb’ oju ayo s’ oke Si agbala orun, K’ a yo lati ri Baba wa Lori ite ife.
Read hymn : mJE k’ agb’ oju ayo s’ okeMO duro de Olorun mi, O si gbo igbe mi, O ri mo simi l’ oro Re, O si mu ‘gbala wa.
Read hymn : MO duro de Olorun miMO fe gbo itan kanna T’ awon Angeli-nso; Bi Oba Ogo ti wa, Gbe aiye osi yi;
Read hymn : MO fe gbo itan kannaMO fe iyera s’ apakan Kuro l’ ero t’ aiye, Ki nf’ akoko iwo orun Kunle gba adura.
Read hymn : MO fe iyera s’ apakanMO fe ki ndabi Jesu, Ninu iwa pele; Ko s’ enit’ o gboro ‘binu L’ enu Re lekan ri.
Read hymn : MO fe ki ndabi JesuMO Fe mo nipa Jesu sii, F’or’ ofe Re h’ elomiran; Ki nle ri ‘gbala kikun Re, Ki ng mo ‘fe ‘ni to ku fun mi.
Read hymn : MO Fe mo nipa Jesu siiMO fe O n’gbagbogbo, Oluwa Olore Ko s’ ohun ti nfun ni L’ alafia bi Tire
Read hymn : MO fe O n’gbagbogbo,MO fe O, Olorun, sugbon Ki se fun ere kan, Ki se nitori’ eniti Ko ba fe O yio ku,
Read hymn : MO fe O, Olorun, sugbonMO feran iwe oro Re; O f’ imole at’ ayo fun Okan okun on ‘banuje! Oro Re t’ oan mi wiwo;
Read hymn : MO feran iwe oro ReMO fi gbogbo re fun Jesu Patapata laiku kan; Ngo ma fe ngo si gbekele, Ngo si ma ba gbe titi.
Read hymn : MO fi gbogbo re fun Jesu