OLURAPADA wa, k’ On to
OLURAPADA wa, k’ On to Dagbere ikehin, O fi Olutunu fun mi, Ti mba wa g be.
Read hymn : OLURAPADA wa, k’ On to643 hymns
OLURAPADA wa, k’ On to Dagbere ikehin, O fi Olutunu fun mi, Ti mba wa g be.
Read hymn : OLURAPADA wa, k’ On toOLUWA alafia wa L’ O pase t’ odun yipo; Awa omo Re wa dupe F’ odun titun t’ a bere.
Read hymn : OLUWA alafia waOLUWA at’ ‘igbala wa, L’ o ko wa jo l’ ale oni, Je ka gbe Ebeneser ro; Odun t’ a ti la koja yi,
Read hymn : OLUWA at’ ‘igbala waOLUWA fi apa Re han, Si jek’a r’ ogo Re, Ki gbogbo wa ri ami Re, K’ o m’ okan lile ro.
Read hymn : OLUWA fi apa Re hanOLUWA ib’ isadi mi, ‘Wo ni mo gbekele; Oro Re gba mi n’ iyanju, Emi erupe ‘le.
Read hymn : OLUWA ib’ isadi mi“OLUWA ji loto:” O wa ko ni ku mo, O wa lati be f’ elese, Ti o ru egan won.
Read hymn : OLUWA ji lotoOLUWA l’ atilehin mi, Kini ‘ba te mi ri? Eniti O da aiye ro, T’ O ta sanma l’ aso.
Read hymn : OLUWA l’ atilehin miOLUWA l’ O nso mi: Y’o te fe mi lorun: Niwon bi a ti je okan, Kil’ emi ‘ba tun fe?
Read hymn : OLUWA l’ O nso miOLUWA mbo aiye o mi Oke y’o sidi n’ipo won; At ‘irawo oju orun, Y’o mu imole won kuro.
Read hymn : OLUWA mbo aiye o miOLUWA mi, mo kepe O Ngo ku b’ O ko ran mi lowo; Jo, fi igbala Re fun mi Gbi mi bi mo ti ri.
Read hymn : OLUWA mi, mo kepe OOLUWA mi, mo njade lo, Lati se ise ojo mi; Iwo nikan l’ emi o mo, L’ oro, l’ ero ati n’ ise.
Read hymn : OLUWA mi, mo njade loOLUWA mo gb’ ohun Re, Ti npe mi wa ‘do Re, Fun ‘wenumo n’nu eje Re T’o san ni Kalfari.
Read hymn : OLUWA mo gb’ ohun Re