OPARI! – l’ Olugbala ke
OPARI! – l’ Olugbala ke, O te ori ba, O si ku; “O pari!” – ire – ije pin, O ti jagun, O si segun.
Read hymn : OPARI! – l’ Olugbala ke643 hymns
OPARI! – l’ Olugbala ke, O te ori ba, O si ku; “O pari!” – ire – ije pin, O ti jagun, O si segun.
Read hymn : OPARI! – l’ Olugbala keOPO ikan omi, Yanrin kekeke; Wonyi l’ o d’ okun nla At’ ile aiye.
Read hymn : OPO ikan omiORE kan mbe fun omode Ninu awon orun; Ore ti ki yipada, T’ ife Re ko le ku;
Read hymn : ORE kan mbe fun omodeORE ni Jesu fun mi, tito ‘b’ Ife Re po, Ife nla ti ko le sa, Bi mo tile s’ aito, S’ife Re yi ni mo ti se;
Read hymn : ORE ni Jesu fun mi, tito ‘b’ Ife Re poORE-OFE! Ohun Adun ni l’ eti wa; Gbongbon re yio gba orun kan, Aiye o gbo pelu.
Read hymn : ORE-OFE! OhunORISUN lai, t’ ayo gbogbo, Ki iyin Re gba enu wa, Nigbat’ a wa sinu ‘le Re, ‘Wo-t’ ore Re buk’ odun wa.
Read hymn : ORISUN lai, t’ ayo gbogboORO die fun Jesu; Ore otito ni; Wa tu okan wa ninu Ohun t’o se fun o.
Read hymn : ORO die fun JesuORU bu koja tan Osan ku si dede: Iboju fere ya T’o bo Olugbala;
Read hymn : ORU bu koja tanORUN si nyara wo, Ojo nku lo; K’ ife ko ji dide, K’ o rubo asale.
Read hymn : ORUN si nyara woORUN, korin! Aiye, yo! Angeli at’ enia, E yi ka b’ O ti ndide, E gbe ‘yin Jesu nyin ga.
Read hymn : ORUN, korin! Aiye, yoOSE, ose rere, Iwo ojo ‘simi; O ye k’ a fi ojo kan, Fun Olorun rere;
Read hymn : OSE, ose rereOSE, ose t’ a nreti A ki o pe “Ma wole,” Iwo ni idunnu wa, A kio s’ ole ninu re.
Read hymn : OSE, ose t’ a nret