WA, enyin olope, wa
WA, enyin olope, wa, Gbe orin ikore ga; Ire gbogbo ti wole K’ otutu oye to de;
Read hymn : WA, enyin olope, wa643 hymns
WA, enyin olope, wa, Gbe orin ikore ga; Ire gbogbo ti wole K’ otutu oye to de;
Read hymn : WA, enyin olope, waWA, iwo isun ibukun, Je ki nkorin ore Re: Odo anu ti nsan titi, Bere orin ‘yin kikan;
Read hymn : WA, iwo isun ibukunWA, jek’ a tun pilese ajo wa, K’ a b’ odun yipo, K’ a ma duro tit’ Oluwa yio fi de.
Read hymn : WA, jek’ a tun pilese ajo waWA, Jesu fi ara han; Wa, je k’okan wa mo O: Wa, mu gbogb’ okan gbona, Wa, bukun wa k’a to lo.
Read hymn : WA, Jesu fi ara hanWA, ma sise, Tani gbodo s’ole ninu oko, Gbati gbogbo enia nkore jo? Kaluku ni Baba pase fun pe, –
Read hymn : WA, ma siseWA, obirin, e ko Orin iye nipa Olugbala, Krist, ‘Mole Olorun,
Read hymn : WA, obirin, e koWA, Oluwa, l’ anu tun wa, Pelu ‘pa ‘p’ okan da, Ongbe ojo np’ oko Sion, Masai ro s’ ori re.
Read hymn : WA, Oluwa, l’ anu tun waWALEJO kan lenu ona: O nkankun je, O ti nkan ri; O ti duro pe, O nduro; Ko s’ ore t’ o je ba lo be.
Read hymn : WALEJO kan lenu onaWO b’ ikore tip o L’ otun l’ osi wa, Alagbase kere L’ ogba Oluwa,
Read hymn : WO b’ ikore tip oWO Imole! larin okun aiye, Ma sin mi lo. Okunkun su, mo si jina s’ ile, Ma sin mi lo.
Read hymn : WO Imole! larin okun aiyeWO kakiri f’ enit’ o s’ alaini, R’ enia lowo loni! Bi ‘ranlowo na si tile kere, R’ enia lowo loni!
Read hymn : WO kakiri f’ enit’ o s’ alainiWO oju sanma ohun ni. Wo lila orun oro. Ji l’ oju orun, okan mi, Dide k’ o si ma sora;
Read hymn : WO oju sanma ohun ni