B’ORUKO Jesu ti dun to
B’ORUKO Jesu ti dun to L’ eti olugbagbo! O tan ‘banuje on ogbe, O le eru re lo.
Read hymn : B’ORUKO Jesu ti dun to643 hymns
B’ORUKO Jesu ti dun to L’ eti olugbagbo! O tan ‘banuje on ogbe, O le eru re lo.
Read hymn : B’ORUKO Jesu ti dun toDAB’ orun sokale, Si fi ara Re han, F’ife Oluwa han F’ edidi Re di wa,
Read hymn : DAB’ orun sokaleDIDE okan mi, nde Gbon eru ebi nu; Ebo eje t’a ru Nitori mi yoju:
Read hymn : DIDE okan mi, ndeDIDE, yin Oluwa, Enyin, ayanfe Re; E f’ okan ati ohun yin, N’ iduro, yin l’ ogo.
Read hymn : DIDE, yin OluwaDIDUN n’ ise na, Oba mi, Lati ma yin oruko Re, Lati se ‘fe Re l’ owuro, Lati so-oro Re l’ale.
Read hymn : DIDUN n’ ise na, Oba miDURO, duro fun Jesu, Enyin om’ogun Krist’: Gbe asia Re s’ oke, A ko gbodo fe ku;
Read hymn : DURO, duro fun Jesu,E DIDE ki a si lorin, K’ a yin Oluwa wa, K’ a si dupe li owo Re, F’ anfani idasi.
Read hymn : E DIDE ki a si lorinE Yin Oluwa, e tun ohun se, Lati korin Re ninu ajo nla; E je k’ aiye yo ninu Eleda won, K’ akobi igbala yo n nu Oba won.
Read hymn : E Yin Oluwa, e tun ohun seEBI ese npa mi l’ eru, O te ori mi ba, Oluwa fi okan eran Paro t’ okuta mi.
Read hymn : EBI ese npa mi l’ eruEFI iyin fun Olorun, E yin, enyin eda aiye, E yin, eyin eda orun. Yin Baba, Omo on Emi.
Read hymn : EFI iyin fun OlorunEFUN ‘pe na kikan, Ipe ihinrere, K’ o dun ja ‘ke ja ‘do, L’ eti gbogbo eda;
Read hymn : EFUN ‘pe na kikanEGBEGBERUN aimoye Nwon wo aso ala, Ogun awon t’a rapada Nwon kun ‘bi ‘mole naa;
Read hymn : EGBEGBERUN aimoye