Yoruba Baptist Hymns
JESU ‘ wo Onisegun nla
First time here? Explore the hymn tools.
Selected words
Verse 1
JESU ‘ wo Onisegun nla,
T’ olokunrun nf’ ailera mo,
Nigba aisan at’ irora,
O se dida ara fun won.
Verse 2
Afoju, aro, alaisan,
Nwon ko sai ri ‘toju re gba,
Torina a wa sodo Re,
A ntoro anu Re nikan.
Verse 3
Irora ti ‘wo la koja,
Jesu ‘Wo le se ‘wosan re,
Awon t’o w’ onisegun nla,
Jo masai se iwosan won.
Verse 4
Oluwa je ki irora,
M’ alaisan tubo sunmo O,
Ki owo egba Re kokan,
Fa asako sunm’ odo Re.
Verse 5
Se ‘wosan okan to gbogbe,
Si gba okan ese wa la,
F’opo ilera Re fun wa,
Ka le ma yin O titilai.
From Yoruba Baptist Hymnshttps://yorubabaptisthymns.com/hymn/jesu-wo-onisegun-nla/
Conversation 0 comments
Share a reflection or ask a question. Comments are reviewed before they appear.
Report a lyric correction
Include the verse and a hymnbook or source reference. Submissions are reviewed before any lyrics change.
Share anonymously
No account is required. Anonymous comments include the city and country you choose to share.