Yoruba Baptist Hymns
NINU gbogbo ewu oru
First time here? Explore the hymn tools.
Selected words
Verse 1
NINU gbogbo ewu oru,
Oluwa l’ O nso wa;
A wa tun ri imole yi,
A tun tee kun ba.
Verse 2
Oluwa pa wa mo loni,
Fi apa Re so wa,
Kiki awon t’ Iwo pamo,
L’o nyo ninu ewu.
Verse 3
K’ oro wa ati iwa wa
Wipe, tire l’ awa;
Tobe k’ imole otito
Le tan l’ oju aiye.
Verse 4
Ma je k’ a pade lodo Re,
Olugbala owon:
Titi a o f’ oju wa ri
Oju Re nikehin.
From Yoruba Baptist Hymnshttps://yorubabaptisthymns.com/hymn/ninu-gbogbo-ewu-oru/
Conversation 0 comments
Share a reflection or ask a question. Comments are reviewed before they appear.
Report a lyric correction
Include the verse and a hymnbook or source reference. Submissions are reviewed before any lyrics change.
Share anonymously
No account is required. Anonymous comments include the city and country you choose to share.