ISE re Oluwa
ISE re Oluwa, Awamaridi ni, Ohun gbogbo ni mu ‘re wa, F’ eni to se ‘fe Re.
Read hymn : ISE re Oluwa643 hymns
ISE re Oluwa, Awamaridi ni, Ohun gbogbo ni mu ‘re wa, F’ eni to se ‘fe Re.
Read hymn : ISE re OluwaISE ‘gbala pari, Jesu ti ba ‘ku ja, O se agbara iboji, O ti di asegun.
Read hymn : ISE ‘gbala pariISIMI wa l’ orun, ko si l’ aiye yi, Emi o se kun, ‘gbat’ iyonu ba de; Simi okan mi, eyikeyi t’ o de, O dun ajo mi ku, o mu k’ ile ya.
Read hymn : ISIMI wa l’ orun, ko si l’ aiye yiISIN l’ o le fun wa li Ayo didun li aiye; Isin ni yio fun wa li Itunu nigba ba ku.
Read hymn : ISIN l’ o le fun wa liISUN kan wa t’o kun f’eje O yo n’iha jesu, Elese mokun ninu re, O bo ninu ebi.
Read hymn : ISUN kan wa t’o kun f’ejeITAN iyanu t’ ife! So fun mi lekan si, Itan iyanu t’ ife! Ti dun l’eti kikan! Awon Angeli rohin re, awon oluso si gbagbo Elese iwo ki yio gbo? Itan iyanu t’ife.
Read hymn : ITAN iyanu t’ ife! So fun mi lekan siITAN kan wa f’ awon orile, Ti yio tun okan won se, Itan otito ti o si dun, Itan alafia on ‘mole,
Read hymn : ITAN kan wa f’ awon orileITANA t’ o bo ‘gbe l’ aso, T’o tutu yoyo be; Gba doje ba kan, a si ku, A subu, a siro.
Read hymn : ITANA t’ o bo ‘gbe l’ asoITE anu! E je k’a lo Lati gba adura; Olorun ‘fe y’o sanu fun Awon t’o nsin nibe.
Read hymn : ITE anu! E je k’a loIWE kan wa ti kika ra, Ko soro fun enia, Ogbon ti awon t’o ka nfe, Ni okan ti o mo.
Read hymn : IWE kan wa ti kika raIWO ha nberu p’ ota yio segun? Okun su lode o sis u ju ninu? Si ferese ati ilekun sile, Jeki ‘ran orun wole.
Read hymn : IWO ha nberu p’ ota yio segunIWO imole okan mi, Li odo Re oru ko si, Ki kuku aiye ma bo O Kuro l’ oju iranse Re.
Read hymn : IWO imole okan mi