JERUSALEM ibi ayo
JERUSALEM ibi ayo, T’ o se owon fun mi; ‘Gbawo n’ ise mi yio pari, L’ ayo, l’ alafia?
Read hymn : JERUSALEM ibi ayo643 hymns
JERUSALEM ibi ayo, T’ o se owon fun mi; ‘Gbawo n’ ise mi yio pari, L’ ayo, l’ alafia?
Read hymn : JERUSALEM ibi ayoJERUSALEM t’ orun, Orin mi, ilu mi! Ile mi bi mba ku, Ekun ibukun mi;
Read hymn : JERUSALEM t’ orunJESU a de l’ ojo oni Lati se ase Re, Jo masai wa si arin wa, K’ O f’ ola Re ran wa.
Read hymn : JESU a de l’ ojo oniJESU a w’ odo Re L’ ojo Re mimo yi; To wa wa ba wa ti pejo, Si ko wa fun ‘ra Re.
Read hymn : JESU a w’ odo ReJESU alail’ abawon, O ti f’ eje Re ra mi, Nko nani ohunkohun, Lehin agbelebu Re.
Read hymn : JESU alail’ abawonJESU awa nwo O fun ‘Wosan alailera yi ‘Wo lo ti se anu nla, F’ abiirun let’ adagun.
Read hymn : JESU awa nwo O funJESU bukun oro Re, K’ o le tete f’ ipa han; Ki elese gbo ‘pe Re, K’ enia Re dagba n’nu ‘fe.
Read hymn : JESU bukun oro ReJESU b’ oluso, ma sin wa, A nfe, ki Re pupo; F’ onje didara Re bow a, Tun agbo Re se fun wa;
Read hymn : JESU b’ oluso, ma sin waJESU fe k’ emi je ‘mole, Ki ntan lojojumo; Nibi gbogbo kin le wu On, N’ ile, ni skul, l’ode.
Read hymn : JESU fe k’ emi je ‘moleJESU fe mi, emi mo; Bibeli so fun mi be; Tire l’ awon omode, Nwon ko l’ agbara, On ni.
Read hymn : JESU fe mi, emi moJESU f’ ara han nitoto, Nibi ase ‘yawo; Oluwa, awa be O, wa F’ ara re han nihin.
Read hymn : JESU f’ ara han nitotoJESU f’ eje Re raw a, E jek’ a sunm’ Olorun; Opo nsina yi wa ka; K’ anu mu wag badura, –
Read hymn : JESU f’ eje Re raw a