LAT’ ori pepe okan wa
LAT’ ori pepe okan wa , Je ki orun dide; Oluwa ma sai ba war u Ebo asale wa.
Read hymn : LAT’ ori pepe okan wa643 hymns
LAT’ ori pepe okan wa , Je ki orun dide; Oluwa ma sai ba war u Ebo asale wa.
Read hymn : LAT’ ori pepe okan waLEHIN aiye buburu yi, Aiye ekun on osi yi, Ibi rere kan wa, Ayipada ko si nibe?
Read hymn : LEHIN aiye buburu yiLEHIN odun die, Lehin igba die, A o ko wa jo pel’ awon Ti o sun n’ iboji.
Read hymn : LEHIN odun dieLEHIN ‘jo mefa t’ O sise, O simi ni ijo keje, O pase fun wa k’ a se be, Ki a si pa ojo na mo.
Read hymn : LEHIN ‘jo mefa t’ O siseLI o wuro Iwo o gbo Ohun mi, Oluwa; S’ odo Re l’ emi o dari Oju adura mi.
Read hymn : LI o wuro Iwo o gboLO kede igbala Jesu Gbogbo enyin onigbagbo Fun ‘rugbin Sharon ka gbogbo, Orile ede aiye yi.
Read hymn : LO kede igbala Jesu“LO wasu Mi,” l’ Oluwa wi: Wi f’ aiye k’ o gba ore Mi; Enit’ o gb’ oro Mi y’o la, En’ti ko gbagbo y’o segbe.
Read hymn : LO wasu Mi,” l’ Oluwa wiLO, l’ oro kutu kutu, Lo, ni osangangan, Lo, ni igba asale, Lo l’ oganjo oru;
Read hymn : LO, l’ oro kutu kutuLODO Re sibe nigbat’ ojumo mo, Ti awon eiye ji, ti kuku lo: Rekoja t’ orun ni didan imole, Idaloju pe, “O wa lodo mi.”
Read hymn : LODO Re sibe nigbat’ ojumo moLONI ni Jesu pe! Asako wa; A! okan okunkun Ma kiri mo.
Read hymn : LONI ni Jesu peL’ AYO l’ a ro t’ ore-ofe Alufa wa l’ oke; Okan Re kun fun iyonu, Aiya Re ntan fun ‘fe.
Read hymn : L’ AYO l’ a ro t’ ore-ofeL’ OJU ale, ‘gbat’ orun wo, Nwon gbe abirun wodo Re: Oniruru ni aisan won, Sugbon nwon f’ayo lo le won
Read hymn : L’ OJU ale, ‘gbat’ orun wo