NGO sunm’ O, Olorun
NGO sunm’ O, Olorun, Ngo sunmo O; B’ o tile se ‘ponju, L’ o mu mi wa;
Read hymn : NGO sunm’ O, Olorun643 hymns
NGO sunm’ O, Olorun, Ngo sunmo O; B’ o tile se ‘ponju, L’ o mu mi wa;
Read hymn : NGO sunm’ O, OlorunNI akoko ipinya, Jeki a fi ara wa, S’ abe oju at’ okan, Ore korikosun wa.
Read hymn : NI akoko ipinyaNI Kanani ti Galili, Nib’ ase ‘gbeyawo, Jesu f’ ara Re han nibe, Pel’ awon ‘mo-ehin.
Read hymn : NI Kanani ti GaliliNI kutu, mo de Oluwa Lati wa oju Re, Okan ongbe mi da ‘ku lo, Lais’ ayo ore Re.
Read hymn : NI kutu, mo de OluwaNIBO n’ isimi wa Fun okan alare? Asan ni lati w’ aiye ka, Lati wa ‘le okun.
Read hymn : NIBO n’ isimi waNIGBA igbi aiye ba dide si o, T’ okan re baje pe gbogbo nkan segbe, Siro ibukun re, ka won lokokan, Enu y’o ya o fun nkan t’ Oluwa t’se.
Read hymn : NIGBA igbi aiye ba dide si oNIGBA itiju k obo mi, Mo f’ eru sa b’ agbelebu; Pelu eru ebi lori, Ife fa mi, mo bo ‘waju,
Read hymn : NIGBA itiju k obo miNIGBA nwon kehin si Sion, A! opo n’ iye won; Mo seb’ Olugbala wipe, ‘Wo fe ko mi pelu?
Read hymn : NIGBA nwon kehin si SionNIGBAKAN ni Betlehemu Ile kekere kan wa; Nib’ iya kan te ‘mo re si Lori ibuje eran;
Read hymn : NIGBAKAN ni BetlehemuNIGBAT’ idanwo yi mi ka, T’ idamu aiye mu mi, Ti Esu wa bi ore mi, Lati wa iparun mi.
Read hymn : NIGBAT’ idanwo yi mi kaNIGBAT’ imole owuro Ba nti ila orun tan wa, A! Orun ododo mimo Ma sai fi anu ran si mi!
Read hymn : NIGBAT’ imole owuroNIGBAT’ ipe ba dun, Ngo dide n’nu ‘boji, Ngo r’ Onidajo Alade, Ri sanma t’ o ngbina.
Read hymn : NIGBAT’ ipe ba dun