Yoruba Baptist Hymns
NIGBA nwon kehin si Sion
First time here? Explore the hymn tools.
Selected words
Verse 1
NIGBA nwon kehin si Sion,
A! opo n’ iye won;
Mo seb’ Olugbala wipe,
‘Wo fe ko mi pelu?
Verse 2
T’ emi t’ okan b’ iru eyi
A fi b’ O di mi mu;
Nko le se kin ma fa sehin
K’ emi si dabi won.
Verse 3
Mo mo, Iwo l’ o l’ agbara
Lati gba otosi;
Odo tani emi o lo,
Bi mo k’ ehni si O?
Verse 4
O da mi loju papa pe
Iwo ni Kristi na!
Enit’ o ni emi iye
Nipa ti eje Re
Verse 5
Ohun Re f’ simi fun mi,
O si l’ eru mi lo;
Ife Re l’ o le mu mi yo
O si to f’ okan mi.
Verse 6
Bi ‘bere yi ti dun mi to,
“Pe emi o lo bi?”
Oluwa ni ‘gbekele Re,
Mo dahan pe, “Beko.”
From Yoruba Baptist Hymnshttps://yorubabaptisthymns.com/hymn/nigba-nwon-kehin-si-sion/
Conversation 0 comments
Share a reflection or ask a question. Comments are reviewed before they appear.
Report a lyric correction
Include the verse and a hymnbook or source reference. Submissions are reviewed before any lyrics change.
Share anonymously
No account is required. Anonymous comments include the city and country you choose to share.