NIHIN l’ awa nje ‘rora
NIHIN l’ awa nje ‘rora, Nihin ni a ma pinya, L’ orun ko si ‘pinya, A! bi yio ti dun to!
Read hymn : NIHIN l’ awa nje ‘rora643 hymns
NIHIN l’ awa nje ‘rora, Nihin ni a ma pinya, L’ orun ko si ‘pinya, A! bi yio ti dun to!
Read hymn : NIHIN l’ awa nje ‘roraNIHIN l’ ayida wa, Ojo, erun nkoja; Ile ni nyan, ti o si nsa, ‘Tana dada si nku;
Read hymn : NIHIN l’ ayida waNIHIN l’ Olorun sin mi de, De ‘hin n’ ipa Re sun ‘jo mi, Gbogbo asale yio si fi Ami ore Re titun han.
Read hymn : NIHIN l’ Olorun sin mi deNIHIN mo j’ alejo, Orun n’ ile. Aginju l’ aiye yi, Orun n’ ile.
Read hymn : NIHIN mo j’ alejoNIHIN, l’ oko Re Oluwa, A ko ‘le ‘rupe yi fun O, Yan fun ‘bugbe Re Pataki, K’ O si so lowo asise.
Read hymn : NIHIN, l’ oko Re OluwaNIHINYI n’ isimi gbe wa, N’iha Re t’ eje nsan; Eyi nikan n’ ireti mi, Pe Jesu ku fun mi.
Read hymn : NIHINYI n’ isimi gbe waNINU gbogbo ewu oru, Oluwa l’ O nso wa; A wa tun ri imole yi, A tun tee kun ba.
Read hymn : NINU gbogbo ewu oruNINU gbogbo iji ti nja, Ninu gbogbo igbi ‘ponju, Abo kan mbe ti o daju, O wa labe ite-anu
Read hymn : NINU gbogbo iji ti njaNINU oru ibanuje, L’ awon egbe ero ayo, Nwon nkorin ‘reti at’ ayo, Nwon nlo s’ ile ileri.
Read hymn : NINU oru ibanujeNIPA ife Olugbala, Ki y’o si nkan; Oju rere Re ki pada. Ki y’o si nkan.
Read hymn : NIPA ife OlugbalaNIWAJU ite anu Re, Jesu, a tun ko ‘ra wa de, A wa toro idariji, Fun majemu t’ a ti baje.
Read hymn : NIWAJU ite anu ReNIWAJU ‘te Jehofa nla, Oril’-ede e f’ ayo sin; Mo p’ On nikan ni Olorun, O le da, Osi le parun.
Read hymn : NIWAJU ‘te Jehofa nla