OJO oni lo tan
OJO oni lo tan, Oru sunmole: Okunkun ti de na, Ile si ti su.
Read hymn : OJO oni lo tan643 hymns
OJO oni lo tan, Oru sunmole: Okunkun ti de na, Ile si ti su.
Read hymn : OJO oni lo tanOJO ‘dajo, ojo, eru! Gbo bi ipe tin dun to! O ju egbarun ara lo, O sin mi gbogbo aiye.
Read hymn : OJO ‘dajo, ojo, eruOJO ‘mole l’ eyi, K’ imole wa l’oni; ‘Wo, Orun, ran s’ okunkun wa, K’o si le oru lo.
Read hymn : OJO ‘mole l’ eyiOJO ‘simi at’ ayo Ojo inu didun, Etutu fun wahala, T’ o dara, t’ o si ndan!
Read hymn : OJO ‘simi at’ ayoOJU ko ti ri, eti ko ti gbo Ese t’ Olugbala pa f’ enia Re, Awon ti O feran, tin won feran Re, Ti nwon nfi ayo sin ninu ile Re.
Read hymn : OJU ko ti ri, eti ko ti gboOJ’ oni lo Jesu Baba, Boju Re w’ emi omo Re.
Read hymn : OJ’ oni loOKAN apata tuba, K’ eje Jesu mu o ro: Wo ara Re ti a gun, Wo bi eje ti bo O,
Read hymn : OKAN apata tubaOKAN are, ile kan mbe, Jina rere s’ aiye ise; Ile t’ ayida ko le de, Tani fe lo simi nibe?
Read hymn : OKAN are, ile kan mbeOKAN mi nsimi, Oluwa; Ngo dupe, ngo ko ‘rin, Okan mi r’ ibi asiri Ti ire ti nsun wa.
Read hymn : OKAN mi nsimi, OluwaOKAN mi pe ninu Jesu: Ko beru ise ofin mo; Erin Olorun dun ninu, Nibit’ o ti kun f’ ese ri.
Read hymn : OKAN mi pe ninu JesuOKAN mi yin Oba orun, Mu ore wa sodo Re; ‘Wo t’ a wo san, t’ a dariji, Tal’ a ba ha yin bi Re?
Read hymn : OKAN mi yin Oba orunOKAN mi, odun kan ninu Aiye re koja lo; Eni ko le gbe ihin pe, Eyi le j’ opin mi.
Read hymn : OKAN mi, odun kan ninu