← Back to the hymnbook
Yoruba Baptist Hymns No. 533

OJU ko ti ri, eti ko ti gbo

Read. Sing. Share.

Verse 1

OJU ko ti ri, eti ko ti gbo
Ese t’ Olugbala pa f’ enia Re,
Awon ti O feran, tin won feran Re,
Ti nwon nfi ayo sin ninu ile Re.

Verse 2

B’ orun ti dun to, ko s’ eni le mo,
Ayo re ko ti la s’ okan eda,
Bi ijoba aiye ba l’ ewu to yi,
Bawo n’ ijoba Olorun yio ti ri?

Verse 3

Ilu ail’ ese ti ko si iku,
Nibiti a ki pe “odigbose,”
Ti ko si ipinya, ti ko si ekun,
Ibiti Jesu joba ti l’ ayo to!

Verse 4

Ipade pelu awon t’ o ti lo,
Baba t’ on t’ omo, oko t’ on t’ ya,
Ore at’ ojulumo t’ a ti saju,
A! b’ ijoba Olorun yio ti dun to!

Verse 5

Pelu awon mimo lati ma ko
Orin Mose ati Od-agutan;
Nibiti ko si aniyan fun ara,
Ti Jesu gbe nsike wa, yio ti dun to!

Verse 6

Ki npadanu aiye on oro re,
K’ ese mi le ilu ogo yi,
Nigba mo ba nrin ita wura l’ oke,
Ngo gbagbe gbogbo iya ti mo ti je.

Conversation 0 comments

Share a reflection or ask a question. Comments are reviewed before they appear.

Share anonymously

No account is required. Anonymous comments include the city and country you choose to share.

Where are you joining from?

Your city and country appear beside your anonymous comment after review.

Form verification is provided by Cloudflare Turnstile.

Sign in to keep track of replies

Report a lyric correction

Include the verse and a hymnbook or source reference. Submissions are reviewed before any lyrics change.

Form verification is provided by Cloudflare Turnstile.Your details are used to respond to this submission.
Support the archive