The hymn library

Browse hymns

643 hymns

No. 622

OLORUN so wa n’nu oko

OLORUN so wa n’nu oko Larin omi jinjin, S’ oluso wa bati nwa lo, Ninu ajin oru. 2. Eru ko ye ki o ba wa, Larin iji ti nja, Niwon gba t’ O wa nitsi Larin omi ti nru. 3. Iparoro ati iji, T’ o nkoja lori ‘le, Iwo ni o da gbogbo won, Nwon wa nikawo Re. 4. Nigbat’ awon Aposteli, Wa lori ‘gbi okun, Ase kan lat’ odo Re wa, Mu dake roro wa. 5. Gbati iji to buru ju, Ba nru l’ atokan wa, Oluwa ma sai ba wag be F’ alafia ba wag be. 6. Ninu wahala aiye yi, Ma se amona wa, Titi ao fi de ‘le rere, Nibi t’ ese ko si.

Read hymn : OLORUN so wa n’nu oko
Support the archive
Made possible by your gifts

Keep the hymns singing.

Help preserve our hymn heritage and keep these songs freely available to everyone.

How often would you like to give?

Available payment methods appear at secure checkout.

Secure payment by Bachs. No website account needed.

Manage my recurring support ↗