OLORUN orile-ede
OLORUN orile-ede, Lat’ ibugbe Re l’ oke, Gbo ebe awon enia Re, K’ O dide si ‘gbala won.
Read hymn : OLORUN orile-ede643 hymns
OLORUN orile-ede, Lat’ ibugbe Re l’ oke, Gbo ebe awon enia Re, K’ O dide si ‘gbala won.
Read hymn : OLORUN orile-edeOLORUN so wa n’nu oko Larin omi jinjin, S’ oluso wa bati nwa lo, Ninu ajin oru. 2. Eru ko ye ki o ba wa, Larin iji ti nja, Niwon gba t’ O wa nitsi Larin omi ti nru. 3. Iparoro ati iji, T’ o nkoja lori ‘le, Iwo ni o da gbogbo won, Nwon wa nikawo Re. 4. Nigbat’ awon Aposteli, Wa lori ‘gbi okun, Ase kan lat’ odo Re wa, Mu dake roro wa. 5. Gbati iji to buru ju, Ba nru l’ atokan wa, Oluwa ma sai ba wag be F’ alafia ba wag be. 6. Ninu wahala aiye yi, Ma se amona wa, Titi ao fi de ‘le rere, Nibi t’ ese ko si.
Read hymn : OLORUN so wa n’nu okoOLORUN ti fi Jesu se Etutu fun ese; On na l’ okan mi duro ti, Ninu igbagbo mi,
Read hymn : OLORUN ti fi Jesu seOLORUN t’ odun tr’ o koja, Iret’ eyi ti mbo; Ib’ isadi wa ni iji, At’ ile wa lailai.
Read hymn : OLORUN t’ odun tr’ o kojaOLORUN wa aiyeraiye, Ore Re ntan loke orun: Oto Re y’o la kuku ja Ti o bo ife Re loju.
Read hymn : OLORUN wa aiyeraiyeOLORUN ‘kore, te ‘ti Re, F’ ara Re han l’ ogun Sion; Ran ojise t’ o n’ itara, T’ o yara lati gb’ ase Re.
Read hymn : OLORUN ‘kore, te ‘ti ReOLORUN ‘yanu! Ona kan Ti o dabi Tire ko si; Gbogb’ ogo ore-ofe Re L’ o farahan bi Olorun.
Read hymn : OLORUN ‘yanu! Ona kanOLORUN! Kini mo ri yi! Opin de f’ohun gbogbo! Onidajo araiye yo, O gunwa n’ite ‘dajo
Read hymn : OLORUN! Kini mo ri yiOLUGBALA mi ha gb’ ogbe? K’ Oba Ogo si ku? On ha je f’ ara Re rubo F’ eni ile b’ emi?
Read hymn : OLUGBALA mi ha gb’ ogbeOLUGBALA, a tun fe f’ ohun kan, Yin oruko Re k’ a to tuka lo; N’ ipari sin, a dide lati yin: A ‘o si kunle fun ibukun Re.
Read hymn : OLUGBALA, a tun fe f’ ohun kanOLUGBALA, gb’ ohun mi, Gb’ ohun mi, gb’ ohun mi; Mo wa sodo Re, gba mi, Nibi agbelebu.
Read hymn : OLUGBALA, gb’ ohun miOLUGBALA, lie se Re L’olote kan wole , O si f’igboiya gb’oju wo ‘Te anu Re loke.
Read hymn : OLUGBALA, lie se Re