WO Oluwa oke
WO Oluwa oke, Ati abe ‘sanma; Mo do bale li ese Re, Mo nke fun anu Re.
Read hymn : WO Oluwa oke643 hymns
WO Oluwa oke, Ati abe ‘sanma; Mo do bale li ese Re, Mo nke fun anu Re.
Read hymn : WO Oluwa okeWO Ore okan ti nkanu! T’ O feran nwon titi d’ opin Eyi n’ ireti mi ro mo, Pe’ “‘Wo o be fun mi.”
Read hymn : WO Ore okan ti nkanuWO ti ngb’ adura igbagbo, O ki ogb’ okan lowo ‘ku T’ o gb’ ara re le O? Emi ko l’ abo fun ‘ra mi,
Read hymn : WO ti ngb’ adura igbagboWO t’ o nbebe f’ ota Re, L’ or’ igi agbelebu; Wipe “Fiji won Baba”, Jesu sanu fun wa.
Read hymn : WO t’ o nbebe f’ ota ReWO t’ O teriba nin’ odo Jordani, T’ O mokun n’nu ‘banuje wa, t’ O si ku T’ O jinde ninu okunkun sin’ ogo, T’ O si gba ‘joba ife awon Tire.
Read hymn : WO t’ O teriba nin’ odo JordaniWO ‘le ‘wo enit’ a bukun, O ki tun s’ alajo; A fi gbogbo okan gba o, ‘Wo arakunrin wa.
Read hymn : WO ‘le ‘wo enit’ a bukunWO ‘le, ‘wo alabukunfun; Wa l’ oruko Jesu owon; A f’ ohun kan ke, “Ma wole,” A ro pe Jesu kio pelu.
Read hymn : WO ‘le, ‘wo alabukunfunWO! b’ o ti dun to lati ri Awon ara t’ o re; Ara ti okan won s’ okan, L’ egbe ide mimo.
Read hymn : WO! b’ o ti dun to lati riWO! gbogbo ile okunkun, Wo! okan mi, duro je; Gbogbo ileri ni o nso T’ ojo ayo t’o l’ ogo;
Read hymn : WO! gbogbo ile okunkunWO! Oluwa l’ awonsanma, O mbo l’ ogo’ l’ ola Re. Enit’ a pa fun elese Mbo pelu Angeli Re:
Read hymn : WO! Oluwa l’ awonsanmaWO, awon t’ o ‘so ala, Nwon duro leti odo, Nwon k’ ehin s’ aiye at’ esu, Nwon ntele Atebomi;
Read hymn : WO, awon t’ o ‘so alaYIKA or’ ite Olorun, Egberun ewe wa; Ewe t’ a dari ese ji, Awon egbe mimo,
Read hymn : YIKA or’ ite Olorun