YBH 239

BI mo egbarun ebun

1. BI mo egbarun ebun,
Ngo di mo Jesu ti a pa,
Y’o je ipile mi;
‘Tori ko s’ ipile miran,
Ti mo le gbe ‘reti mi ka,
Lehin Jesu nikan,

2. Mo ni Kristi ni gbogbo mi,
Ogbon, ipa at’ ododo,
Ati iwa pipe;
L’ oruko Re mo n’ igboiya,
Lati sunmo Oba orun;
Mo pade are Re.

3. Ko s’ ona si ayo orun,
S’ ayo at’ alafia toto,
Lehin Jesu, Ona;
Jek’ a rin l’ ona mimo na,
K’ a f’ igbagbo ko ‘rin titi;
Ao fi ba A joko.

(Visited 269 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you