YBH 323

GBEKE re le Oluwa

1. GBEKE re le Oluwa,
F’ oro Re s’ agbara re;
Y’o duro ti o lailai,
B’ orun tile koja lo.

2. N’nu gbogbo iji aiye,
‘Wo o ma r’ itunu Re,
Gbo ileri iranwo,
P’, “Emi ni, mase beru.”

3. K’ aniyan re w’ odo Re,
Duro l’ agbegbe ite,
On yio fa o l’owo,
Yio mu o de ‘le rere.

4. K’ aniyan re w’ odo Re,
Ni wakati wahala,
Nje gb’ ara le oro Re,
Gbeke re le Oluwa.

(Visited 610 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you