YBH 483

OLORUN t’ odun tr’ o koja

1. OLORUN t’ odun tr’ o koja,
Iret’ eyi ti mbo;
Ib’ isadi wa ni iji,
At’ ile wa lailai.

2. Labe ojiji ite Re
L’ awon enia Re ngbe!
Tito l’ apa Re nikanso,
Abo wa si daju.

3. K’ awon oke k’ o to duro,
Tabi k’ a to d’ aiye,
Lailai Iwo ni Olorun,
Bakanna, l’ ailopin!

4. Olorun t’ odun t’ o t’ o koja,
Iret’ eyi ti mbo,
Ma s’ abo wa ‘gba ‘yonu de,
At’ ile wa lailai.

(Visited 7,247 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you