YBH 74

IWO ti gbogbo eda nsin

1. IWO ti gbogbo eda nsin
L’ ara erupe yi,
Bi O tit obi to l’aiye!
B’ ogo Re ti po to!

2. Nigbati mo f’ iyanu wo
Ogo ‘se Re l’ oke,
Osupa ti njoba l’ oru,
At’ irawo tin tan.

3. Oluwa kil’ enia ti
‘Wo fe ma ronu re?
Tab’ iran re t’ Iwo ‘ba ma
S ore to to yi fun?

4. Iwo ti gbogbo eda nsin
L’ ara erupe yi,
Bi O tit obi to l’ aye!
B’ ogo Re ti po to.

(Visited 279 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you