AGOGO ihinrere
AGOGO ihinrere Nlu lat’ ilu de ‘lu ‘Bukun ati ‘gbala ofe, Ni nwon fun o at’ emi,
Read hymn : AGOGO ihinrere643 hymns
AGOGO ihinrere Nlu lat’ ilu de ‘lu ‘Bukun ati ‘gbala ofe, Ni nwon fun o at’ emi,
Read hymn : AGOGO ihinrereAJAGUN Jesu l’ emi bi, At’ omo ehin Re? Ngo ha beru lati wasu Agbara isin Re?
Read hymn : AJAGUN Jesu l’ emi biAJIGBESE anu ni mi, Mo ti ba majemu mi je; Laifoya ninu pipe Re, Mo gb’ ara at ore mi wa.
Read hymn : AJIGBESE anu ni miAKO ha gb’ oro wuwo ni, P’ a sin wa pelu Oluwa? P’ a te wa ri sinu ‘ku Re, A sib o ara osi ‘le.
Read hymn : AKO ha gb’ oro wuwo niAKO n’ ibugbe kan nihin, Eyi ba elese n’nu je; Ko ye k’ enia mimo kanu, ‘Tori nwon nfe ‘simi t’ orun.
Read hymn : AKO n’ ibugbe kan nihinAKOKO ati lo mi ya, Mo gb’ ohun to npe mi lo ‘le, Olorun jek’ iyonu pin, Jek’ iranse Re ku l’ ayo.
Read hymn : AKOKO ati lo mi yaAKOKO ‘re gbat’ eda te, Lati b’ Olorun re s’ oro, Lati f’ edun ranse s’ oke, Ati lati gb’ oro mimo.
Read hymn : AKOKO ‘re gbat’ eda teALABUKUN n’ isun eje, T’ a fi han elese aiye; Olubukun n’ om Olorun, Nipa ‘na Re la wow a san,
Read hymn : ALABUKUN n’ isun ejeALABUKUN n’nu Jesu Ni awon om’ Olorun Ti a fie je Re ra Lati ‘nu iku s’ iye;
Read hymn : ALABUKUN n’nu JesuALAFIA pel’ Oluwa, A, ede wo l’ eyi! A f’ eje b’ elese la ‘ja, Oto ‘simi l’ eyi.
Read hymn : ALAFIA pel’ OluwaALAFIA w’ okan, t’ ohun re Ko apata l’ ohun aro: Dekun ejo wi, pa ‘nu mo, Ki ekun ye san l’ oju re;
Read hymn : ALAFIA w’ okan, t’ ohun reALAFIA, li aiye ese yi, Eje Jesu nwipe, “Alafia!”
Read hymn : ALAFIA, li aiye ese yi