Yoruba Baptist Hymns
AKOKO ‘re gbat’ eda te
First time here? Explore the hymn tools.
Selected words
Verse 1
AKOKO ‘re gbat’ eda te,
Lati b’ Olorun re s’ oro,
Lati f’ edun ranse s’ oke,
Ati lati gb’ oro mimo.
Verse 2
Gbat’ aniyan aiye jowo
Ijoba aiya re lowo,
T’ ohun gbogbo nfi paroro
So ti ojo ‘simi’ mimo.
Verse 3
Gbat’ Olorun pa sunmo ni,
Lati f’ ayo gbo t’ enia Re,
Lati f’ opin si arokan,
Lati tan ekun asofo.
Verse 4
Ibanigbe Re ni fun ni,
Ni itowo ayo ti mbo,
Ni so ‘le aiye d’ ile re,
Ati ona ‘bode orun.
From Yoruba Baptist Hymnshttps://yorubabaptisthymns.com/hymn/akoko-re-gbat-eda-te/
Conversation 0 comments
Share a reflection or ask a question. Comments are reviewed before they appear.
Report a lyric correction
Include the verse and a hymnbook or source reference. Submissions are reviewed before any lyrics change.
Share anonymously
No account is required. Anonymous comments include the city and country you choose to share.