Yoruba Baptist Hymns
AJAGUN Jesu l’ emi bi
First time here? Explore the hymn tools.
Selected words
Verse 1
AJAGUN Jesu l’ emi bi,
At’ omo ehin Re?
Ngo ha beru lati wasu
Agbara isin Re?
Verse 2
Ao ha gbe mi g’ oke orun
Lori ‘busun ‘rorun,
Gbati opo ja f’ ere na
Lori okun eje?
Verse 3
Ko ha s’ ota lati ba ja?
Ti mo ni lati ko?
Aiye ha ba or’-ofe t’y’o
Mu mi d’ oro Re je?
Verse 4
Mo ni ja bi ngo ba joba;
Oluwa, pelu mi;
Ngo f’ ara da gbogbo ise,
Pelu iranwo Re.
Verse 5
B’ awon enia Re tile ku,
Nwon o segun ‘ja na,
Nwon ri isegun l’ okere,
Eru ko sib a won.
Verse 6
Gb’ ojo t’ o l’ ogo nib a de,
T’ awon ogun Re ndan;
Ninu aso ‘segun l’ oke,
Ogo yio je Tire.
From Yoruba Baptist Hymnshttps://yorubabaptisthymns.com/hymn/ajagun-jesu-l-emi-bi/
Conversation 0 comments
Share a reflection or ask a question. Comments are reviewed before they appear.
Report a lyric correction
Include the verse and a hymnbook or source reference. Submissions are reviewed before any lyrics change.
Share anonymously
No account is required. Anonymous comments include the city and country you choose to share.