Yoruba Baptist Hymns
YO awon ti nsegbe, sajo eni nku
First time here? Explore the hymn tools.
Selected words
Verse 1
YO awon ti nsegbe, sajo eni nku,
F’ anu ja won kuro ninu ese,
Ke f’ awon ti nsina, gb’ eni subu ro,
So fun won pe, Jesu le gba won la,
Yo awon ti nsegbe, sajo eni nku,
Alanu ni Jesu, yio gbala.
Verse 2
Bi nwon o tile gan, sibe O nduro
Lati gb’ omo t’ o ronupiwada;
Sa f’ itara ro won, sir o won jeje,
On o dariji, bi nwon ba gbagbo.
Verse 3
Yo awon ti nsegbe, – ise tire ni;
Oluwa yio f’ agbara fun o:
Fi suru ro won, pada s’ ona toro,
So f’ asako p’ Olugbala ti ku,
From Yoruba Baptist Hymnshttps://yorubabaptisthymns.com/hymn/yo-awon-ti-nsegbe-sajo-eni-nku/
Conversation 0 comments
Share a reflection or ask a question. Comments are reviewed before they appear.
Report a lyric correction
Include the verse and a hymnbook or source reference. Submissions are reviewed before any lyrics change.
Share anonymously
No account is required. Anonymous comments include the city and country you choose to share.