Yoruba Baptist Hymns
OG’ Oluwa j’ ohun ‘yanu
First time here? Explore the hymn tools.
Selected words
Verse 1
OG’ Oluwa j’ ohun ‘yanu,
Ona Re si yato;
Ko si j’ ohun t’ o wu eda,
Lati fi iyin fun.
Verse 2
Ibukun ni f’ awon t’ a fun
L’ oye lati mo pe,
Olorun wa pelu awon,
Bi nwon ko tile ri.
Verse 3
Ibukun ni f’ awon t’ o mo
‘Biti oto gbe wa,
Ti nwon si mu ipa rere,
T’ o wo l’ oju eda.
From Yoruba Baptist Hymnshttps://yorubabaptisthymns.com/hymn/og-oluwa-j-ohun-yanu/
Conversation 0 comments
Share a reflection or ask a question. Comments are reviewed before they appear.
Report a lyric correction
Include the verse and a hymnbook or source reference. Submissions are reviewed before any lyrics change.
Share anonymously
No account is required. Anonymous comments include the city and country you choose to share.