YIN Olorun Abra’am
YIN Olorun Abra’am, T’ o gunwa lok’ orun, Eni agba aiyeraiye, Olorun ife;
Read hymn : YIN Olorun Abra’am643 hymns
YIN Olorun Abra’am, T’ o gunwa lok’ orun, Eni agba aiyeraiye, Olorun ife;
Read hymn : YIN Olorun Abra’amYIN Olorun Oba wa, E ko orin ogo si, ‘Tor’ anu Re wa sibe, L’ ododo dajudaju.
Read hymn : YIN Olorun Oba waYIN Olorun Oba wa; E gbe ohun iyin ga; Anu Re o wa titi, L’ ododo dajudaju.
Read hymn : YIN Olorun Oba waYIN Oluwa, orun wole Yin enyin mimo l’ oke K’ orun at’ osupa ko, K’ awon ‘rawo f’ iyin fun.
Read hymn : YIN Oluwa, orun woleYIN ‘Luwa, okan mi; Ki gbogbo inu mi, Ba mi yin oruko Eni T’ ife Re po julo.
Read hymn : YIN ‘Luwa, okan miYO awon ti nsegbe, sajo eni nku, F’ anu ja won kuro ninu ese, Ke f’ awon ti nsina, gb’ eni subu ro, So fun won pe, Jesu le gba won la,
Read hymn : YO awon ti nsegbe, sajo eni nkuYO, eyin onigbagbo, Je k’ imole nyin tan; Igba ale mbo tete, Oru si fere de.
Read hymn : YO, eyin onigbagbo