OLUWA ji loto
“OLUWA ji loto:” O wa ko ni ku mo, O wa lati be f’ elese, Ti o ru egan won.
Read hymn : OLUWA ji loto“OLUWA ji loto:” O wa ko ni ku mo, O wa lati be f’ elese, Ti o ru egan won.
Read hymn : OLUWA ji lotoKABO ojo rere, ” l’ ao ma wi titi; A sete ‘ku loni, orun di tiwa. ‘Wo oku d’ alaye, oba tit’ aiye, Gbogb’ eda Re, Jesu, ni nwon njuba Re.
Read hymn : KABO ojo rere, ” l’ ao ma wi titiALLELUYA! Alleluya!! Alleluya!!! Ija d’ opin, ogun si tan: Olugbala jagun molu: Orin ayo l’ a o ma ko. Alleluya!
Read hymn : ALLELUYA! Alleluya!! Alleluya!!!HALLELUYAH, Halleluyah, E gbe ohun ayo ga, E korin inudidun, K’ e si yin olorun wa,
Read hymn : HALLELUYAH, HalleluyahJESU ye; titi aiye Eru iku ko ba ni mo; Jesu ye; nitorina Isa oku ko n ‘ipa mo. – Alleluya!
Read hymn : JESU ye; titi aiyeOLUWA mbo aiye o mi Oke y’o sidi n’ipo won; At ‘irawo oju orun, Y’o mu imole won kuro.
Read hymn : OLUWA mbo aiye o miOLORUN! Kini mo ri yi! Opin de f’ohun gbogbo! Onidajo araiye yo, O gunwa n’ite ‘dajo
Read hymn : OLORUN! Kini mo ri yiJESU t’o k’o gb’aiye la, Jinde kuro ninu oku, Nipa agbara Re; A da, sile lowo iku,
Read hymn : JESU t’o k’o gb’aiye laBELESE s’owo po, Ti nwon nde s’Oluwa, Dimo si Kristi Re, Lati gan Oba na,
Read hymn : BELESE s’owo poL’OWURO, Ojo ajinde, T’ara t’okan y’o pade, Ekun, ‘kanu on irora Y’o d’opin.
Read hymn : L’OWURO, Ojo ajindeORU bu koja tan Osan ku si dede: Iboju fere ya T’o bo Olugbala;
Read hymn : ORU bu koja tanENYIN t’e f’oluwa, T’o mo ‘pa Re, e wa, E dapo n.isokan, Lati yin ore Re;
Read hymn : ENYIN t’e f’oluwa