WO! Oluwa l’ awonsanma
WO! Oluwa l’ awonsanma, O mbo l’ ogo’ l’ ola Re. Enit’ a pa fun elese Mbo pelu Angeli Re:
Read hymn : WO! Oluwa l’ awonsanmaWO! Oluwa l’ awonsanma, O mbo l’ ogo’ l’ ola Re. Enit’ a pa fun elese Mbo pelu Angeli Re:
Read hymn : WO! Oluwa l’ awonsanmaOLORUN Olurapada, Mo ri ‘se mi nin’ oro Re, Ninu ‘gbe aiye Re nihin, Ofin f’ ara han gedegbe.
Read hymn : OLORUN OlurapadaGBA t’ Olugbala w’ aiye, Anu j’ oba l’ okan Re, O nfi ibakedun han K’ O si gan enikeni.
Read hymn : GBA t’ Olugbala w’ aiyeA WON eye n’ ife, Kolokolo n’ iho, enia n’ ile: Eda n’ ib’ isimi Sugbon Jesu ko r’ ibi gborile.
Read hymn : A WON eye n’ ifeKRIST’ ki ‘joba Re de, Ki ase Re bere; F’ opa-rin Re fo Gbogbo ipa ese.
Read hymn : KRIST’ ki ‘joba Re deEMI, Olore ofe, Tan ‘mole Re s’ okan mi; M’ eru ebi mi kuro; F’ ife Re orun kun mi.
Read hymn : EMI, Olore ofeWA Emi Mimo, wa, Pelu ipa t’ orun, Si ran ninu anu Re nla Sor’ okan okun wa.
Read hymn : WA Emi Mimo, waOLURAPADA wa, k’ On to Dagbere ikehin, O fi Olutunu fun mi, Ti mba wa g be.
Read hymn : OLURAPADA wa, k’ On toWA, Emi ‘re, ‘Dada orun Pelu itunu lat’ oke; S’ alabo at’ Oluto wa, To ero at’ isise wa.
Read hymn : WA, Emi ‘re, ‘Dada orunEMI Mimo, ‘Dada orun, Wa li agbara Re; K’ o da ina ife mimo, Si okan tutu wa.
Read hymn : EMI Mimo, ‘Dada orunEMI orun, gb’ adura wa, Wa gbe ‘nu ile yi, Sokale pel’ agbara Re, Wa, Emi Mimo wa.
Read hymn : EMI orun, gb’ adura waEMI anu, oto, ife, Ran agbara Re t’ oke wa; Mu iyanu ojo oni, De opin akoko gbogbo.
Read hymn : EMI anu, oto, ife