OLORUN ‘yanu! Ona kan
OLORUN ‘yanu! Ona kan Ti o dabi Tire ko si; Gbogb’ ogo ore-ofe Re L’ o farahan bi Olorun.
Read hymn : OLORUN ‘yanu! Ona kanOLORUN ‘yanu! Ona kan Ti o dabi Tire ko si; Gbogb’ ogo ore-ofe Re L’ o farahan bi Olorun.
Read hymn : OLORUN ‘yanu! Ona kanJI, okan mi dide l’ ayo, Korin iyin Olugbala; Ola Re bere orin mi, ‘Seun ife Re ti po to!
Read hymn : JI, okan mi dide l’ ayoA! mba le l’ egberun ahon. Fun ‘yin Olugbala, Ogo Olorun Oba mi, Isegun ore Re.
Read hymn : A! mba le l’ egberun ahonEYO, eyin mimo, e yin Ibukun; anu, igbala, Jesu oke nyin titi lai, D’ oju ko agbara iji.
Read hymn : EYO, eyin mimo, e yinJESU Od’-agutan, ‘Wo t’ O ta ‘je Re le, Lati gba wa lowo ‘parun, Gba iyin ailopin.
Read hymn : JESU Od’-agutanIRO t’ o dun ju orin, Fa mi l’ oruko Jesu, Gbogbo ‘reti okan mi Wa lor’ agbelebu Re.
Read hymn : IRO t’ o dun ju orinIFE t’ o rekoja ero, T’ o se ‘lana rere, Fun ‘gbala enia, ki Adam T’ o mu isubu wa.
Read hymn : IFE t’ o rekoja eroIFE mi s’ ibi ti wa pe, Lai beru itiju, Titi mo fi r’ ohun titun, Ti o da mi duro.
Read hymn : IFE mi s’ ibi ti wa peKI sepe mo ko yan O, Oluwa, ko ri be, Okan mi iba ko O, Sugbon ‘Wo l’ o yan mi.
Read hymn : KI sepe mo ko yan OODODO Re nikan laise t’ emi, L’ o le se isimi fun okan mi; Ife Re l’ o le mu k’ ifoiya lo, L’ o le da iji okan mi l’ ekun.
Read hymn : ODODO Re nikan laise t’ emiEWE ti Oba orun, Korin didun b’ e ti nlo; Korin ‘yin t’ Olugbala, Ise Enit’ o l’ ogo.
Read hymn : EWE ti Oba orunAJIGBESE anu ni mi, Mo ti ba majemu mi je; Laifoya ninu pipe Re, Mo gb’ ara at ore mi wa.
Read hymn : AJIGBESE anu ni miOKAN mi yin Oba orun, Mu ore wa sodo Re; ‘Wo t’ a wo san, t’ a dariji, Tal’ a ba ha yin bi Re?
Read hymn : OKAN mi yin Oba orunYIN Olorun Abra’am, T’ o gunwa lok’ orun, Eni agba aiyeraiye, Olorun ife;
Read hymn : YIN Olorun Abra’amFUN aanu t’ o po b’ iyanrin, Ti mo ngba lojojo Lat’ odo Jesu Oluwa, Kili emi le tun?
Read hymn : FUN aanu t’ o po b’ iyanrinITE anu! E je k’a lo Lati gba adura; Olorun ‘fe y’o sanu fun Awon t’o nsin nibe.
Read hymn : ITE anu! E je k’a loNINU gbogbo iji ti nja, Ninu gbogbo igbi ‘ponju, Abo kan mbe ti o daju, O wa labe ite-anu
Read hymn : NINU gbogbo iji ti njaIKOSE ti po to, t’ a nri Li ona wa s’ ite anu Sibe, tani mo ‘yi adua Ti ki y’o fe ma wa nibe.
Read hymn : IKOSE ti po to, t’ a nriLODO Re sibe nigbat’ ojumo mo, Ti awon eiye ji, ti kuku lo: Rekoja t’ orun ni didan imole, Idaloju pe, “O wa lodo mi.”
Read hymn : LODO Re sibe nigbat’ ojumo moJE, Oluwa, sin wa jeje, L’ aiye omije yi ja, Si fun wa l’ ore-ofe Re Ninu eru wa gbogbo:
Read hymn : JE, Oluwa, sin wa jejeNGO sunm’ O, Olorun, Ngo sunmo O; B’ o tile se ‘ponju, L’ o mu mi wa;
Read hymn : NGO sunm’ O, OlorunOLORUN lat’ oro d’ ale, Wakati wo l’ o dun pupo, B’ eyi t’ o pe mi wa ‘do Re Fun adua?
Read hymn : OLORUN lat’ oro d’ aleWA k’ a da m’ awon ore wa Ti nwon ti jere na; N’ ife k’ a f’ okan ba won lo S’ ode orun lohun.
Read hymn : WA k’ a da m’ awon ore waGBA alare nwa sinmi, Ti nwon w’odo Re; Gba nwon ko ‘banuje won Wa si ‘waju Re;
Read hymn : GBA alare nwa sinmi