ESE ti e ko le sailo
ESE ti e ko le sailo Emi nyin danu lor’ asan, Ti ohun kanso, na t’ o ye, Ko si n’nu gbogbo ero nyin?
Read hymn : ESE ti e ko le sailo643 hymns
ESE ti e ko le sailo Emi nyin danu lor’ asan, Ti ohun kanso, na t’ o ye, Ko si n’nu gbogbo ero nyin?
Read hymn : ESE ti e ko le sailoETUN won ko fun mi ki ngbo Oro ‘yanu t’ Iye! Je ki nsi tun ewa won ri, Oro ‘yanu t’ Iye,
Read hymn : ETUN won ko fun mi ki ngboEWA otosi elese, Wa li akoko anu; Jesu nduro lati gba nyin, O kun fun ‘fe at’ ipa;
Read hymn : EWA otosi eleseEWE ti Oba orun, Korin didun b’ e ti nlo; Korin ‘yin t’ Olugbala, Ise Enit’ o l’ ogo.
Read hymn : EWE ti Oba orunEWOLE f’ Oba, ologo julo, E korin ipa ati ife Re; Alabo wa ni, at’ Eni Igbani, O ngbe ‘nu ogo, eleru ni iyin.
Read hymn : EWOLE f’ Oba, ologo juloEYI l’ ojo Oluwa da, O pe ‘gba na n Tire; K’ orun ko yo, k’ aiye k’ o yo, K’ iyin y’ ite na ka.
Read hymn : EYI l’ ojo Oluwa daEYI, e yipada, ese t’ e o ku, Nigbat’ Olorun sunmo wa li anu? Jesu npe nyin, Emi sin wipe k’ e wa, Angeli si nduro lati mu nyin lo.
Read hymn : EYI, e yipada, ese t’ e o kuEYO gbogb’ orile-ede N’ iwaju Ob’ Alade yin, E sin pelu inudidun, Fi gbogbo ahon yin l’ ogo.
Read hymn : EYO gbogb’ orile-edeEYO Jesu joba N’nu omo enia, O da ara tubu, O so won d’omnira:
Read hymn : EYO Jesu jobaEYO, eyin mimo, e yin Ibukun; anu, igbala, Jesu oke nyin titi lai, D’ oju ko agbara iji.
Read hymn : EYO, eyin mimo, e yinFI ibukun Re tu wa ka, Fi ayo kun okan wa; K’ olukuluku mo ‘fe Re, K’ a l’ ayo n’ nu ore Re,
Read hymn : FI ibukun Re tu wa kaFUN aanu t’ o po b’ iyanrin, Ti mo ngba lojojo Lat’ odo Jesu Oluwa, Kili emi le tun?
Read hymn : FUN aanu t’ o po b’ iyanrin