EYO gbogb’ orile-ede
EYO gbogb’ orile-ede N’ iwaju Ob’ Alade yin, E sin pelu inudidun, Fi gbogbo ahon yin l’ ogo.
Read hymn : EYO gbogb’ orile-edeEYO gbogb’ orile-ede N’ iwaju Ob’ Alade yin, E sin pelu inudidun, Fi gbogbo ahon yin l’ ogo.
Read hymn : EYO gbogb’ orile-edeEYO Jesu joba N’nu omo enia, O da ara tubu, O so won d’omnira:
Read hymn : EYO Jesu jobaFI ibukun Re tu wa ka, Fi ayo kun okan wa; K’ olukuluku mo ‘fe Re, K’ a l’ ayo n’ nu ore Re,
Read hymn : FI ibukun Re tu wa kaFUN aanu t’ o po b’ iyanrin, Ti mo ngba lojojo Lat’ odo Jesu Oluwa, Kili emi le tun?
Read hymn : FUN aanu t’ o po b’ iyanrinFUN mi n’ iwa pele, Okan tutu; Ifarabale bi T’ Oluwa mi;
Read hymn : FUN mi n’ iwa peleFUNRUGBIN l’ owuro, Ma simi tit’ ale; F’ eru on ‘yemeji sile Ma fon s’ ibi gbogbo.
Read hymn : FUNRUGBIN l’ owuroFUN ‘rugbin l’ owuro, irugbin inu ‘re Funrugbin l’ osan gan, ati ni ale Duro de ikore ati ‘gba ikojo A o f’ ayo pada, ru iti wole.
Read hymn : FUN ‘rugbin l’ owuro, irugbin inu ‘reF’ AWON enia Re t’ o lo ‘simi Awon ti o f’ igbagbo jewo Re, Ki yin oruko Re, Olugbala, Alleluya!
Read hymn : F’ AWON enia Re t’ o lo ‘simiF’ ERU re f’ afefe, N’ ireti, ma foya, Olorun gbo ‘mikanle re, Yiop gb’ ori re ga.
Read hymn : F’ ERU re f’ afefeF’ORUKO Jesu s’ okan re Om’ egbe on ‘banuje; Yio fun o l’ayo oun ‘tunu Gbee wo lo s’ibi gbogbo
Read hymn : F’ORUKO Jesu s’ okan reF’ ORUK’ Olorun loke, T’ O l’ agbara at’ ola, Olorun ibi gbogbo, N’ iyin ati ogo wa.
Read hymn : F’ ORUK’ Olorun lokeGBA aiye mi, Oluwa, Mo ya si mimo fun O; Gba gbogbo akoko mi, Ki nwon kun fun iyin Re.
Read hymn : GBA aiye mi, Oluwa