JESU Or’ elese mo de
JESU Or’ elese mo de, Em’ otosi wa fun ‘rawo, Ara mi su mi fun ese, Na apa Re gba mi s’ ile.
Read hymn : JESU Or’ elese mo deJESU Or’ elese mo de, Em’ otosi wa fun ‘rawo, Ara mi su mi fun ese, Na apa Re gba mi s’ ile.
Read hymn : JESU Or’ elese mo deJESU o ye ki nl’ ayo, Ti mba le gbekele O, Pe ogbon Re to to mi, Pe ore Re to pese,
Read hymn : JESU o ye ki nl’ ayoJESU pe omode, O gbe won s’ aiya Re; O f’ owo Re gba won mora, O si sure fun won.
Read hymn : JESU pe omodeJESU ti mo gbeke mi le, At’ ireti mi lo s’ orun: Mo r’ ipa Re, ngo si tele Ona Re titi ngo fi ri.
Read hymn : JESU ti mo gbeke mi leJESU t’ asia Re bow a, O f’ onje m’ okan way o; O te ase siwaju wa, T’ a f’ eran ara Re se.
Read hymn : JESU t’ asia Re bow aJESU t’o k’o gb’aiye la, Jinde kuro ninu oku, Nipa agbara Re; A da, sile lowo iku,
Read hymn : JESU t’o k’o gb’aiye laJESU t’ O wa gba mi la, Wo ‘nu odo Jordani, O jade kuro n’nu re, A si m’ O l’ Om’-Olorun,
Read hymn : JESU t’ O wa gba mi laJESU wipe k’ a ma sora Ni wakati gbogbo, O si nf’ emi isoji fun Awon t’ o mbere re.
Read hymn : JESU wipe k’ a ma soraJESU ye; titi aiye Eru iku ko ba ni mo; Jesu ye; nitorina Isa oku ko n ‘ipa mo. – Alleluya!
Read hymn : JESU ye; titi aiyeJESU y’o joba ni gbogbo Ibit’ a ba le ri orun; ‘Joba Re y’o tan kakiri, ‘Joba Re ki o n’ ipekun.
Read hymn : JESU y’o joba ni gbogboJESU ‘ wo Onisegun nla, T’ olokunrun nf’ ailera mo, Nigba aisan at’ irora, O se dida ara fun won.
Read hymn : JESU ‘ wo Onisegun nlaJI, apa Olorun, k’ o ji, Gbe ‘pa Re wo, mi or’ ile; Ni sisin Re, je k’ aiye ri Isegun ise anu Re.
Read hymn : JI, apa Olorun, k’ o jiJI, enyin mimo ji, E k’ ojo owo yi, E fi orin iyin At’ ayo juba Re;
Read hymn : JI, enyin mimo jiJI, okan mi, dide giri, Ma lepa nso kikan; F’ itara sure ije yi F’ orun, f’ ade iye.
Read hymn : JI, okan mi, dide giriJI, okan mi dide l’ ayo, Korin iyin Olugbala; Ola Re bere orin mi, ‘Seun ife Re ti po to!
Read hymn : JI, okan mi dide l’ ayoJI, ‘wo Kristian, k’ o ki oro ayo Ti a bi Olugbala araiye; Dide, k’ o korin ife Olorun, T’ awon Angeli nko n’ ijo kini,
Read hymn : JI, ‘wo Kristian, k’ o ki oro ayoJINNA kuro n’ ibugbe enia, L’ a gbo ‘gbe awon adete mewa: Jesu sanu fun won, se wosan won Okan l’ o wa dupe, Mesan ha da?
Read hymn : JINNA kuro n’ ibugbe eniaJI okan mi, ba orun ji, Mura si ise ojo re; Ma se ilora, ji kutu, K’ o san ‘gbese ebo oro.
Read hymn : JI okan mi, ba orun jiJI ‘se Re nde Jesu! Fi agbara Re han! Fo ‘hun t’ o le j’ oku dide Je k’ enia Re gbo.
Read hymn : JI ‘se Re nde Jesu!KABO ojo rere, ” l’ ao ma wi titi; A sete ‘ku loni, orun di tiwa. ‘Wo oku d’ alaye, oba tit’ aiye, Gbogb’ eda Re, Jesu, ni nwon njuba Re.
Read hymn : KABO ojo rere, ” l’ ao ma wi titiKABO ojo ‘simi T’ o r’ ajinde Jesu; Ma bowa s’ okan ti nsoji, At’ oju ti nyo yi!
Read hymn : KABO ojo ‘simiK AWA to pari eko wa, Awa f’ iyin fun O; ‘Tori ojo Re mimo yi, Jesu Ore ewe.
Read hymn : K AWA to pari eko waKEFERI nsegbe lojojo, Egbegberun l’ o nkoja lo; Mura Kristian s’igbala won, Wasu fun won ki nwon to ku.
Read hymn : KEFERI nsegbe lojojoKI a to d’ awon oke nla, Tabi ki aiye to duro, Ki a to da awon igba, ‘Wo l’ Olorun lat’ ibere.
Read hymn : KI a to d’ awon oke nla