KIKU n’nu Jesu, iku re
KIKU n’nu Jesu, iku re T’ a ki ji sinu re sokun, Isimi t’ o ni itura, Ti iku ko le yo lenu.
Read hymn : KIKU n’nu Jesu, iku reKIKU n’nu Jesu, iku re T’ a ki ji sinu re sokun, Isimi t’ o ni itura, Ti iku ko le yo lenu.
Read hymn : KIKU n’nu Jesu, iku reKIL’ o le w’ ese mi nu? Ko si, lehin eje Jesu; Kil’ o tun le wo mi san? Ko si, lehin eje Jesu.
Read hymn : KIL’ o le w’ ese mi nuKINI gbogbo lala Re L’ ori mi fun, Jesu, At’ anfani t’ O fun mi Ju awon miran lo?
Read hymn : KINI gbogbo lala ReKI nko ohun gbogbo sile Fun O, Oluwa mi O to be, niwon b’ O ti se Rekoja ‘yi fun mi.
Read hymn : KI nko ohun gbogbo sileA! ese mi poju O pon koko; Adale, adale, Ni mo ndese!
Read hymn : KI se l’ ainiretiKI sepe mo ko yan O, Oluwa, ko ri be, Okan mi iba ko O, Sugbon ‘Wo l’ o yan mi.
Read hymn : KI sepe mo ko yan OKO mi, Oluwa mi, Ki nr’ owo Re yika, Ki nsi ma se ohun gbogbo, Bi enipe fun O.
Read hymn : KO mi, Oluwa miKO mi ni iwon ojo mi, Iwo Eleda mi; Mo fe w’ ona toro aiye, Ki nmo ailera mi.
Read hymn : KO mi ni iwon ojo miKO mi Oluwa bi a ti Je gbohungbo oro Re; B’ O ti wa mi je k’ emi wa, Awon omo Re t’ o ti nu.
Read hymn : KO mi Oluwa bi a tiKO si ewa nibikan ti Mo le fi we ti Krist’: Ohun t’ oku, Oluwa, ni K’ a je ‘kan pelu Re.
Read hymn : KO si ewa nibikan tiKO s’ aye ‘jafara nihin Fun ‘reti at’ eru aiye; B’ emi ki ba pe bo, B’ o ba je pe b’ Onidajo
Read hymn : KO s’ aye ‘jafara nihinKO s’ ohun t’ o ku kin se, B’ o ti wu k’ o kere; Jesu ku, O san gbogbo Igbese ti mo je.
Read hymn : KO s’ ohun t’ o ku kin seKo s’ ona si ayo orun, S’ ayo at’ alafia toto, Lehin Jesu, Ona; Jek’ a rin l’ ona mimo na,
Read hymn : Ko s’ ona si ayo orunKO s’ ore bi Jesu onirele, Ko s’ okan! Ko s’ okan! Ko s’ elomi t’ o le w’ okan wa san, Ko s’ okan! Ko s’ okan!
Read hymn : KO s’ ore bi Jesu onireleKO to k’ awon mimo beru, Ki nwon so ‘reti nu; ‘Gba nwon ko reti ‘ranwo Re, Olugbala yio de.
Read hymn : KO to k’ awon mimo beruKRIST, ologo, olola, Iwo Imole aiye, Orun ododo, dide, K’ O si bori okunkun;
Read hymn : KRIST, ologo, ololaKRISTIAN ma ti wa ‘simi, Beli angeli re nwi, Ni arin ota l’ owa, Ma sora.
Read hymn : KRISTIAN ma ti wa ‘simi,KRISTI fun gbogb’ aiye Ise nla naa bere Egbegberun ni gbogb’ aiye, Nfe gb’ oro ‘mo ‘Lorun
Read hymn : KRISTI fun gbogb’ aiyeKRISTI n’ ipile wa, Lori Re lao kole; Awon mimo nikan, L’ o ngb’ agbala orun.
Read hymn : KRISTI n’ ipile waKRIST’, nin’ ogba Eden, L’ a gbe ti ri r’ ase yi, Ase Tire, P’ o ye f’ eni meji
Read hymn : KRIST’, nin’ ogba EdenKRIST’ ki ‘joba Re de, Ki ase Re bere; F’ opa-rin Re fo Gbogbo ipa ese.
Read hymn : KRIST’ ki ‘joba Re deKRIST’ Oluwa ji loni, – Halleluyah, Eda at’ Angeli nwi – Hal. Gb’ ayo at’ isegun ga – Hal. K’ orun at’ aiye gberin! – Hal.
Read hymn : KRIST’ Oluwa ji loni, – HalleluyahK’ A to sun, Olugbala wa, Fun wa n’ ibukun ale; A jewo ese wa fun O, Iwo l’o le gba wa la.
Read hymn : K’ A to sun, Olugbala waK’ OLORUN so o, k’ a tun pade Ki imoran Re gbe o ro, K’ O ka o mo agutan Re, K’ Olorun so o, k’ a tun pade!
Read hymn : K’ OLORUN so o, k’ a tun pade