GBA ‘Wo Onidajo ba de
GBA ‘Wo Onidajo ba de Lati m’ awon Tire lo ‘le, Ngo ha wa l’ arin won? Ao ha r’ ekolo lasan yi,
Read hymn : GBA ‘Wo Onidajo ba de643 hymns
GBA ‘Wo Onidajo ba de Lati m’ awon Tire lo ‘le, Ngo ha wa l’ arin won? Ao ha r’ ekolo lasan yi,
Read hymn : GBA ‘Wo Onidajo ba deGBAGBO awon ‘ya wa, ‘gbagbo aaye Nn’ orin at’adura, ale; N’ alo at’ ife eba ina, Ibagbe re si wa yi wa ka,
Read hymn : GBAGBO awon ‘ya wa, ‘gbagbo aayeGBAT, a b’Oluwa rin N’nu ‘mole oro Re Ona wa yi o ti l’ogo to! ‘Gbat’ a ba nse f’e Re
Read hymn : GBAT, a b’Oluwa rinGBATI ipe Oluwa ba dun T’ akoko ba si pin, T’ imole owuro mimo ntan lailai; Gbat’ awon t’ a ti gbala,
Read hymn : GBATI ipe Oluwa ba dunGBATI mo ri agbelebu, Ti a kan Oba-ogo mo, Mo ka gbogbo oro s’ ofo, Mo kegan gbogbo ogo mi.
Read hymn : GBATI mo ri agbelebu,GBATI Samueli ji To ‘igb’ ohun Eleda Ni gbolohun kokan, Ayo re ti po to
Read hymn : GBATI Samueli jiGBATI ‘ji goke l’ ona re, T’ o f’ aniyan kun okan mi, N’ gbekele w’ oke, wipe, “Mo mo p’ Oluwa wa n’ tosi.”
Read hymn : GBATI ‘ji goke l’ ona reGBAT’ a kun fun ‘banuje, Gb’ omije nsan l’ oju wa, Gbat’ a nsokun, t’ a nsofo, Olugbala, gbo ti wa.
Read hymn : GBAT’ a kun fun ‘banuje,GBAT’ aiye yi ba koja, Ti orun re ba si wo, Ti a ba wo ‘nu ogo, T’ a bojuwo ehin wa;
Read hymn : GBAT’ aiye yi ba kojaGBAT’ emi re ba fo lo, T’ iku ba siji bo o; ‘Gbati sa re ba pari, Elese n’ bo l’ o yo si?
Read hymn : GBAT’ emi re ba fo loGBAT’ O ba de, gbat’ O ba de, Lati sir’ oso Re; Gbogb’ oso Re iyebiye, Awon ti O fe!
Read hymn : GBAT’ O ba de, gbat’ O ba deGBAT’ oju mi ba se peki ‘Mole to se n’ ila orun, Orun ododo masai ran Ase anu re s’ ori mi,
Read hymn : GBAT’ oju mi ba se peki