GBO elese, Anu npe o
GBO elese, Anu npe o, Ohun didun l’Ofi npe O nke yara w’Olugbala, K’owo are to subu;
Read hymn : GBO elese, Anu npe oGBO elese, Anu npe o, Ohun didun l’Ofi npe O nke yara w’Olugbala, K’owo are to subu;
Read hymn : GBO elese, Anu npe oGBOGBO aiye, gbe jesu ga, Angeli’, e wole fun: E mu ade Oba Re wa, Se l’Oba awon oba.
Read hymn : GBOGBO aiye, gbe jesu gaKo ‘s okunkun fun wa t’ o wa t’ o wa ‘nu Jesu, Imole aiye ni Jesu! A nrin n’ imole b’ a ntel’ amona wa, Imole aiye ni Jesu.
Read hymn : GBOGBO aiye ti nu s’ okunkun eseGBOGBO eda dapo, E jo yin Oluwa, E pa ohun nyin po Lati fe oro na;
Read hymn : GBOGBO eda dapoGBOGBO eda labe orun. E fi iyin fun Eleda wa: Ki gbogbo orile-ede Ko Olugbala wa l’ orin.
Read hymn : GBOGBO eda labe orunGBOGBO eje eran, Ti pepe awon ju, Ko le f’ okan l’ Alafia, Ko le we eri nu.
Read hymn : GBOGBO eje eranGBOGB’ ogun orun nro keke, Angeli mu harpu won, Awon mimo nt’ ohun won se Lati josin t’ o l’ ogo;
Read hymn : GBOGB’ ogun orun nro kekeGBO l’ or’ ite Re, Alade, F’ oniruru ‘bukun ranse, B’ awon omo Re ti nwa O, Gb’ adura t’ oro Re ko ni.
Read hymn : GBO l’ or’ ite Re, AladeGBO ohun alore, Ji, ara, ji: Jesu ma fere, de, Ji, ara, ji
Read hymn : GBO ohun aloreGBO ohun Jesu ti nke pe, Tani yio sise loni? Oko pon pupo sise loni? Tani yio lo ka a?
Read hymn : GBO ohun Jesu ti nke peGBO ohun t’ o dun lat’ oke Si Jesu l’ odo Jordani, Eri fun gbogbo araiye, “Eyi l’ ayanfe Omo Mi.”
Read hymn : GBO ohun t’ o dun lat’ okeGBO okan mi, bi Angeli ti nkorin, Yika orun ati yika aiye; E gbo bi oro orin won ti dun to! Ti nso ‘gbati ese ki y’o si mo:
Read hymn : GBO okan mi, bi Angeli ti nkorin