JESU npe wa l’ osan, l’ oru
JESU npe wa l’ osan, l’ oru Larin irumi aiye; Lojojumo l’ a ngb’ ohun Re Wipe, “Kristian, tele Mi.”
Read hymn : JESU npe wa l’ osan, l’ oruJESU npe wa l’ osan, l’ oru Larin irumi aiye; Lojojumo l’ a ngb’ ohun Re Wipe, “Kristian, tele Mi.”
Read hymn : JESU npe wa l’ osan, l’ oruWA sodo Jesu, mase duro, N’ oro Re l’ O ti f’ ona han wa, O duro li arin wa loni, O nwi jeje pe, “Wa.”
Read hymn : WA sodo Jesu, mase duroGBO okan mi, bi Angeli ti nkorin, Yika orun ati yika aiye; E gbo bi oro orin won ti dun to! Ti nso ‘gbati ese ki y’o si mo:
Read hymn : GBO okan mi, bi Angeli ti nkorin“WA sodo Mi, alare Ngo fun nyin n’ isimi.” A! ohun didun Jesu, Ti o p’ elese wa,
Read hymn : WA sodo Mi, alareNIGBAT’ idanwo yi mi ka, T’ idamu aiye mu mi, Ti Esu wa bi ore mi, Lati wa iparun mi.
Read hymn : NIGBAT’ idanwo yi mi kaJESU nigba ‘danwo, Gbadua fun mi; K’ emi ma ba se O, Ki nsi sako lo:
Read hymn : JESU nigba ‘danwoELESE wa sodo Jesu Enit’ O wa gba o la Enit’ O gbe are re wo, Lati irora re.
Read hymn : ELESE wa sodo JesuOKAN mi, sunmo ‘te anu, Nibi Jesu ngb’ ebe, F’ irele wole l’ ese Re, ‘Wo ko le gbe nibe.
Read hymn : OKAN mi, sunmo ‘te anuLO, l’ oro kutu kutu, Lo, ni osangangan, Lo, ni igba asale, Lo l’ oganjo oru;
Read hymn : LO, l’ oro kutu kutuPADA asako s’ ile re, Baba re l’ O npe o; Ma se alarinkiri mo, N’nu ese at’ osi.
Read hymn : PADA asako s’ ile reOMO Olorun nlo s’ ogun Lati gb’ ade Oba: Opagun Re si nfe, lele, Tal’ o s’ om-ogun Re?
Read hymn : OMO Olorun nlo s’ ogunOLORUN npe, ngo ha s’ aigbo? Ngo ha s’ afe aiye d’ owon? Odun y’o ha ma rekoja K’ okan mi ma togbe sibe?
Read hymn : OLORUN npe, ngo ha s’ aigbo