O HA le je p’ a mi
O HA le je p’ a mi? Olugbala ha yan mi? Bi ebi mi tip o to O ha da oruko mi?
Read hymn : O HA le je p’ a miO HA le je p’ a mi? Olugbala ha yan mi? Bi ebi mi tip o to O ha da oruko mi?
Read hymn : O HA le je p’ a miMO ha le tun duro Laif’ ini mi toro? Ki nmu okan kuro l’ aiye, Ki ngba Olugbala?
Read hymn : MO ha le tun duroWO ti ngb’ adura igbagbo, O ki ogb’ okan lowo ‘ku T’ o gb’ ara re le O? Emi ko l’ abo fun ‘ra mi,
Read hymn : WO ti ngb’ adura igbagboBABA, mo n’ owo mi si O; Nko mo ‘ranwo miran: Bi O ba kuro lodo mi, A! nibo ni ngo lo?
Read hymn : BABA, mo n’ owo mi si OJESU, Ore ‘lese ni O; B’ elese, mo now O; Lat’ inu ekun ife Re, Oluwa, ranti mi.
Read hymn : JESU, Ore ‘lese ni OBI mo ti ri – laisawawi, Sugbon nitori eje Re, B’O si ti pe mi pe ki nwa – Olugbala, mo de.
Read hymn : BI mo ti ri – laisawawiTIRE l’ ola Baba, O wa n’ ikawo Re; B’ ojum’ ola si mo ba ni, Nipa ase Re ni.
Read hymn : TIRE l’ ola BabaELESE; – mo nfe ‘bukun; Onde; – mo nfe d’ omnira; Alare; – mo nfe ‘simi; “Olorun sanu fun mi.”
Read hymn : ELESE; – mo nfe ‘bukunEREDI irokeke yi Ti enia ti now koja? ‘Jojumo n’ iwojopo na, Eredi re tin won nse be?
Read hymn : EREDI irokeke yiJINNA kuro n’ ibugbe enia, L’ a gbo ‘gbe awon adete mewa: Jesu sanu fun won, se wosan won Okan l’ o wa dupe, Mesan ha da?
Read hymn : JINNA kuro n’ ibugbe eniaWA, Jesu fi ara han; Wa, je k’okan wa mo O: Wa, mu gbogb’ okan gbona, Wa, bukun wa k’a to lo.
Read hymn : WA, Jesu fi ara hanNIHINYI n’ isimi gbe wa, N’iha Re t’ eje nsan; Eyi nikan n’ ireti mi, Pe Jesu ku fun mi.
Read hymn : NIHINYI n’ isimi gbe wa