IFE l’ Olorun: anu Re
IFE l’ Olorun: anu Re Mole s’ ona wa gbogbo; O ns’ ayo ji, O ndin ‘se ku: Ogbon nla ni olorun.
Read hymn : IFE l’ Olorun: anu ReIFE l’ Olorun: anu Re Mole s’ ona wa gbogbo; O ns’ ayo ji, O ndin ‘se ku: Ogbon nla ni olorun.
Read hymn : IFE l’ Olorun: anu ReIFE mi s’ ibi ti wa pe, Lai beru itiju, Titi mo fi r’ ohun titun, Ti o da mi duro.
Read hymn : IFE mi s’ ibi ti wa peIFE orun! alailegbe! N’nu ase mimo yi, Ogo re kun, ‘mole re po, Ti ntan iye jade.
Read hymn : IFE orun! alailegbeIfe orun, o ti dun to! Gbawo ni ngo ri t’okan mi, Y’o kun fun kiki re? Okan mi npongbe lati mo
Read hymn : Ife orun, o ti dun toIFE orun alailegbe, Ayo orun sokale: Fi okan wa se ‘bugbe Re, Se asetan anu Re;
Read hymn : IFE orun alailegbeIFE orun t’ o teriba Lati pin ninu ekun wa: Iwo l’ a k’ aniyan wa le, Ko si nkan gbat’ O sunmo wa.
Read hymn : IFE orun t’ o teribaIFE Re da wa si loni, L’ are a si dubule; Ma so wa n’ idake orun, K’ ota ma yow a l’enu:
Read hymn : IFE Re da wa si loniIFE t’ o rekoja ero, T’ o se ‘lana rere, Fun ‘gbala enia, ki Adam T’ o mu isubu wa.
Read hymn : IFE t’ o rekoja eroIGBAGBO l’ ategun t’ o so Orun at’ aiye po; On l’ Olugbala fi sise Iyanu Re l’ aiye.
Read hymn : IGBAGBO l’ ategun t’ o soIGBAGBO mi duro l’ori, Eje at’ododo Jesu; Nko je gbekele ohun kan, Lehin oruko nla Jesu;
Read hymn : IGBAGBO mi duro l’oriIGBAGBO mi nwo O, Iwo Od’-agutan, Olugbala Jo gbo adua mi,
Read hymn : IGBAGBO mi nwo OIGBALA ni, igbala ni, Awa elese nfe; Nitori ninu buburu, T’ a se l’ awa nsegbe.
Read hymn : IGBALA ni, igbala ni