Ife orun, o ti dun to
Ife orun, o ti dun to! Gbawo ni ngo ri t’okan mi, Y’o kun fun kiki re? Okan mi npongbe lati mo
Read hymn : Ife orun, o ti dun to643 hymns
Ife orun, o ti dun to! Gbawo ni ngo ri t’okan mi, Y’o kun fun kiki re? Okan mi npongbe lati mo
Read hymn : Ife orun, o ti dun toIFE Re da wa si loni, L’ are a si dubule; Ma so wa n’ idake orun, K’ ota ma yow a l’enu:
Read hymn : IFE Re da wa si loniIFE t’ o rekoja ero, T’ o se ‘lana rere, Fun ‘gbala enia, ki Adam T’ o mu isubu wa.
Read hymn : IFE t’ o rekoja eroIGBA wa mbe li owo Re, A fe ko wa nibe; A fie mi at’ ara wa Si abe iso Re.
Read hymn : IGBA wa mbe li owo ReIGBAGBO l’ ategun t’ o so Orun at’ aiye po; On l’ Olugbala fi sise Iyanu Re l’ aiye.
Read hymn : IGBAGBO l’ ategun t’ o soIGBAGBO mi duro l’ori, Eje at’ododo Jesu; Nko je gbekele ohun kan, Lehin oruko nla Jesu;
Read hymn : IGBAGBO mi duro l’oriIGBAGBO mi nwo O, Iwo Od’-agutan, Olugbala Jo gbo adua mi,
Read hymn : IGBAGBO mi nwo OIGBALA ni, igbala ni, Awa elese nfe; Nitori ninu buburu, T’ a se l’ awa nsegbe.
Read hymn : IGBALA ni, igbala niIJA ti de, ipe sin dun kikankikan, “Wo ‘hamora!” nigbe jake-jado; Oluwa omo-ogun nlo si isegun, Ko pe ti segun Krist’ y’o farahan.
Read hymn : IJA ti de, ipe sin dun kikankikanIJINLE l’ oro Re, Jesu, Tani le tumo re? Tani gbon to! tani mo to! Tal’ oye re po to!
Read hymn : IJINLE l’ oro Re, JesuIKOSE ti po to, t’ a nri Li ona wa s’ ite anu Sibe, tani mo ‘yi adua Ti ki y’o fe ma wa nibe.
Read hymn : IKOSE ti po to, t’ a nriIKU l’ opin ohun gbogbo; B’ o ti wu k’ emi gun, Egun ni ko le sai ma se T’ a ti fi eda gun.
Read hymn : IKU l’ opin ohun gbogbo